azlyrics.biz
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

dj afrobeat, q dot & olamide – ibadan lyrics

Loading...

bi sekere ba ti dun oo
konga a te le
a te le
ijo ma tele
antrans ko gi le o fun mi jaree
lateko de challengi
a gba guru mara ji
awole pelu bugati
ankara lori fasasi
idi n be nibadan o
oke be nibadan o
idi arere idi adire
oke sango oke mo po
ema je ko di ja
olosho yapa ni bodija o
pelu sokoto pe n pe
awon omo mi ni mo lete
alomo metta feya speaker
furo rabata fe ya b-mber
them say them to buggi down
ibadan ni mo wa o
ibadan ni mo re o
ibadan ni mo wa o
ibadan ni mo re o
be wa deko be ba ni le
ibadan ni mo wa oo
e shoutout si awon omo uni
leed city de badan poly
ebami ki kunle silencer
omo musulumi to fa poli
ero to lo london
ebami ki kayode kida
tiringbeku teletele
omo ibadan to di n-gg-
omo woli to n fa taba
basira su sara ko ta nba
obo’kan fe ya ogun lada
won de ni momo re fe your fada
qdot fe silekun fe kun
o’yo tan owa bekun bekun
i turn up tan osi seku
ka to fi enu ifa lele odi seven
ni le oluyole ooo
awon omo lagelu
ujo sokky mo gbe wa o
no be skelewu
atana wole pelu sanpeni
ki ni a de temi complaini
pe owo afefe la fi sustaini
ahhen ti naira ba ti tan
mabinu ma ko pounsi jade
ko fun mi lolosho to wo gown
won fun mi lorogbo to ti brown
eyi ko lemaso fun wa
pe oshogbo ti di town
eeeeen we rocking gucci gucci
ajoko sori chair kusin
eran chikin la gbe ah nu jawee
ikorodu li’ogawa ooo
nanana na’nanana
ile oluyole omo’afikarawun foko’mu



Random Lyrics

HOT LYRICS

Loading...