9ice - mio momo lyrics
yee, yee+
mí o mọmọ
bi ń bá m’ọti yo délé
mummy, don’t blame me
mí o mọmọ o (mí o mọmọ)
bi ń bá gbo’wó wálé
daddy, don’t blame me
mí o mọmọ o (mí o mọmọ)
mí o mọmọ o (mí o mọmọ)
o ṣéṣí ni
mí o mọmọ o (mí o mọmọ)
don’t you give up
the girl such you know what’s up
as a prodigal son, i know when to stop
i go club from friday to sunday
on weekdays, i run birthday party
i’m hoping for someday
when moon go come my way
durela dey there that day
when money miss road, come my way
i carry am come home
owó inú shaka
i carry am come home
owó inú shaka
bi ń bá m’ọti yo délé
mummy, don’t blame me
mí o mọmọ o (mí o mọmọ)
bi ń bá gbo’wó wálé
daddy, don’t blame me
mí o mọmọ o (mí o mọmọ)
mí o mọmọ o (mí o mọmọ)
o ṣéṣí ni
mí o mọmọ o (mí o mọmọ)
mummy mi, daddy mi, eee
this na god doing o, yeee+
daddy mi, mummy mi
this na god blessing o, yee, uhh+
ọmọ burúkú o lọjọ ti ẹ o
e no easy, if e easy, na set up
someway, someday, any which way
we can make our pay
mo r’owó, mo gbé wálé
ẹ mà ṣe ba mí wí, o ṣéṣí ni
bi ń bá m’ọti yo délé
mummy, don’t blame me
mí o mọmọ o (mí o mọmọ)
bi ń bá gbo’wó wálé
daddy, don’t blame me
mí o mọmọ o (mí o mọmọ)
mí o mọmọ o (mí o mọmọ)
o ṣéṣí ni (yeah)
mí o mọmọ o (mí o mọmọ)
everywhere that i’ve been
no be me dey buy the drink
awọn tèmi lo ń ṣ’áyé fún mí
so, nothing if i no get drunk
make i no do skunk, if i no dey blunt
do stuff, do stunt
feeling high
it’s what we are out here for
all i can see is dom pérignon
moët, rosé cannot reach us all
all i can see is an no buy here
and we are down for whatever (whatever)
whenever (whenever), however
bi ń bá m’ọti yo délé (however)
mummy, don’t blame me
mí o mọmọ o (mí o mọmọ)
bi ń bá gbo’wó wálé
daddy, don’t blame me
mí o mọmọ o (mí o mọmọ)
mí o mọmọ o (mí o mọmọ)
o ṣéṣí ni
mí o mọmọ o (mí o mọmọ)
bi ń bá m’ọti yo délé
mummy, don’t blame me
mí o mọmọ o (mí o mọmọ)
bi ń bá gbo’wó wálé
daddy, don’t blame me
mí o mọmọ o (mí o mọmọ)
mí o mọmọ o (mí o mọmọ)
o ṣéṣí ni
mí o mọmọ o (mí o mọmọ)
bi ń bá gbo wo wálé
daddy, don’t blame me
mi o mọmọ o (mi o mọmọ)
Random Lyrics
- kolektyw fala - jestem fala lyrics
- autumn j - after all lyrics
- money man - clear lyrics
- slaves of the feeling - bad influence lyrics
- official53crew - glory lyrics
- katastrofa - окутала меня луна (the moon enveloped me) lyrics
- arabs in aspic - god requires insanity lyrics
- jesco (nl) - the cuckoo lyrics
- d$ luqi - xilofone lyrics
- benny the butcher & black soprano family - knightfall lyrics