aṣa - iba lyrics
everyday, so god…
bacause of you. i dey live, i dey breath, i dey eat
so, i wanna have some talk with you
orun, silekun i wanna have some talk, [with] you o (2xe)
nitori re mose n lola
nitori re mose n s’oge
nitori re mose n ra moto
mowole, m’oboluwa mi soro
nitori re mose wa laye
nitori re mose n woso sara
nitori re moji l’owuro
mow’aye mi lode ye
a o, aa a o o ibafeledu’a
a o, aa a o o
mowole, m’obolowa mi soro
nitori re mose n gbo iroyin ayo
lais’owo laisi nkankan
iya oni, layoola o
b’oluwa tiwi, be naa lori
jiji moji lowuro
moji si inu ipese re
ayo at’alafia ye ye
o, o o oni pe ki n ma se beru
a o, aa a o o ibafeledu’a
a o, aa a o o
mowole, m’obolowa mi soro
melo la fe so
melo lo si n bowa
melo la fe so, eh
melo lo si n bowa
nitori re mose n sa ko, everyday, eh eh
nitori re mojijo lese mi, oh oh oh, oh oh
ninu iponju, ninu idamu
b’ebi ba n p’ona
mawole, maboluwa mi soro
b’emi o le yan
baye ba foju dimi
b’emi o le ni
mawole, maboluwa mi soro
a o, aa a o o ibafeledu’a
a o, aa a o o
mowole, m’obolowa mi soro
ninu iponju, ninu idamu
b’ebi ba n p’ona
mawole, maboluwa mi soro
mioni foju sunkun mo o
aye loja, oh oh… orun… orunile
and that’s fine by me… eh eh…
oh… ye ye… bring it down… oh oh…
Random Lyrics
- de-phazz - devil's music lyrics
- xman (american rapper) - partly sunny lyrics
- codigo 13 - gritos do silêncio lyrics
- adverse - fuckwithmeyouknowigotit lyrics
- stricken city - pull the house down lyrics
- metaphorce - vpodrum 04 (zhika) lyrics
- fabrizio de andré - giugno '73 lyrics
- olympians - pasxalis - to sxoleio lyrics
- rafa blas - vivir morir lyrics
- raige - ulisse lyrics