apostle ruben agboola jp - mo ni ki ndupe lyrics
[intro + chorus]
ko ni dúpẹ́
mo kọ ní dúpẹ́ ni
ko ni dúpẹ́
mo kọ ní dúpẹ́ ni
fún ọrẹ tí jésù ṣé
mo kọ ni dúpẹ́
fún ọrẹ tí jésù ṣé
mo kọ ni dúpẹ́ ni
[chorus]
ko ni dúpẹ́
mo ko ni dúpẹ́
mo ni dúpẹ́
mo kọ ní dúpẹ́ ni
fún ọrẹ tí jésù ṣé
mo kọ ni dúpẹ́
fún ọrẹ tí jésù ṣé
mo kọ ni dúpẹ́ ni
[verse]
ágbáni lágbá tón ni
òré olódodo ní
o dabo bomi o
ọtun pọn mí lé
[chorus]
ko ni dúpẹ́
mo ko ni dúpẹ́
mo ni dúpẹ́
mo kọ ní dúpẹ́ ni
fún ọrẹ tí jésù ṣé
mo kọ ni dúpẹ́
fún ọrẹ tí jésù ṣé
mo kọ ni dúpẹ́ ni
[verse]
kí gbọ́gbọ́ ènìyàn gbé ga
kí gbọ́gbọ́ ẹ̀yán gbé ga
fun ẹnì tó kú nítorí wá o
àpáta ayérayé
o jìyà nítorí wá
nítorí gbọ́gbọ́ ènìyàn ní
o fẹ mi rẹ lèlé
ẹ̀jẹ̀ kí a dúpẹ́ ọ̀rẹ́ tí jésù se
[chorus]
ko ni dúpẹ́
mo ko ni dúpẹ́
mo ni dúpẹ́
mo kọ ní dúpẹ́ ni
fún ọrẹ tí jésù ṣé
mo kọ ni dúpẹ́
fún ọrẹ tí jésù ṣé
mo kọ ni dúpẹ́ ni
[pre+chorus]
há! ẹgbẹ́ mí é w’asia
bí tí nfẹ lélẹ̀
ogún jésù fèrè dé náà
a’fere ségun (a’fere ṣẹ́gun)
d’odi mù, ẹ̀mí fẹrẹ dé (d’odi mù, ẹ̀mí fẹrẹ dé)
beni jésù nwi (beni jésù nwi)
rán’dáhùn padà s’orun, pé (rán’dáhùn padà s’orun, pé)
àwa ọ dí mú (àwa ọ dí mú)
[chorus]
ko ni dúpẹ́
mo ko ni dúpẹ́
mo ni dúpẹ́
mo kọ ní dúpẹ́ ni
fún ọrẹ tí jésù ṣé
mo kọ ni dúpẹ́
fún ọrẹ tí jésù ṣé
mo kọ ni dúpẹ́ ni
[outro + chorus]
ko ni dúpẹ́
mo ko ni dúpẹ́
mo ni dúpẹ́
mo kọ ní dúpẹ́ ni
fún ọrẹ tí jésù ṣé
mo kọ ni dúpẹ́
fún ọrẹ tí jésù ṣé
mo kọ ni dúpẹ́ ni
Random Lyrics
- soan arhimann - vous retrouver lyrics
- goga (rus) - fлипаю купюры (fleeping cupures) lyrics
- unlymited - big food lyrics
- nataša đorđević - živ mi ti lyrics
- frankie rose - doa lyrics
- drowsyy - северное сияние (northern lights) lyrics
- tit sweat - trauma fetish lyrics
- gentlemens club & blazer boccle - bitter lyrics
- progisthename - summer time 16's lyrics
- dillanponders - can’t stop lyrics