apostle ruben agboola jp - un o ma gbe o ga lyrics
un o ma gbé o ga
un o ma gbé o ga
un o ma gbé o ga bàbá
un o ma gbé o ga
un o ma gbé o ga
un o ma gbé o ga
un o ma gbé o ga bàbá
un o ma gbé o ga
fún ọrẹ re
fún anu tó fi dá mí si
ọlọ́run ayérayé
un o ma gbe o ga bàbá
un o ma gbé o ga
un o ma gbé o ga
un o ma gbé o ga
un o ma gbé o ga bàbá
un o ma gbé o ga
oje kí ad’òkú
be lon fún wá loúnjẹ je
ọlọ́run tó ga ju
kò mú ayé wa lọ, ẹsè sir
un o ma gbé o ga
un o ma gbé o ga
un o ma gbé o ga bàbá
un o ma gbé o ga
fún ifẹ tí ẹni sì wa
fún ọrẹ re
lórí gbọ́gbọ́ ayé
lórí gbọ́gbọ́ ènìyàn
lórí ọmọ ọlọ́run
lórí ilẹ̀ dé yi
ati ni gbọ́gbọ́ àgbáyé
un o ma gbé o ga bàbá
un o ma gbé o ga ẹsẹ̀
un o ma gbé o ga
un o ma gbé o ga
un o ma gbé o ga bàbá
un o ma gbé o ga
olúwa, ọlọ́run mi ató bí ju
olúwa, ọlọ́run mi ìwọ lọba
olúwa, ọlọ́run mi ató bí ju
olúwa, ọlọ́run mi ìwọ l’ọba
olúwa, ọlọ́run bàbá lóla
olúwa, ọlọ́run akande lede
olúwa, ọlọ́run mi ató bí ju
olúwa, ọlọ́run mi ìwọ l’oba
olúwa, ọlọ́run mi ató bí ju
olúwa, ọlọ́run mi ìwọ lọba
olúwa, ọlọ́run mi ató bí ju
olúwa, ọlọ́run mi ìwọ l’ọba
olúwa, ọlọ́run obadare
olúwa, ọlọ́run adeboye
olúwa, ọlọ́run bàbá jide
olúwa, ọlọ́run mi ató bí ju
olúwa, ọlọ́run mi ìwọ l’oba
olúwa, ọlọ́run mi ató bí ju
olúwa, ọlọ́run mi ìwọ l’ọba
olúwa, ọlọ́run mi ató bí ju
olúwa, ọlọ́run mi ìwọ l’ọba
ọlọ́run àwọn tó ti lọ
bàbá kú ìṣe
ọlọ́run àwọn iranse
bàbá kú ìṣe o
ọlọ́run àwọn olórin
bàbà kú ìṣe
ọlọ́run arike
bàbá kú ìṣe o
ọlọ́run davidi
bàbá kú ìṣe
ọlọ́run gbolaye
bàbá kú ìṣe o
ọlọ́run àwọn àgbà gba
bàbá kú ise
ọlọ́run baba kú ìṣe
bàbà ku ise o
ọlọ́run tó ron mi nise
olúwa, ọlọ́run ató bí ju
olúwa, ọlọ́run mi ìwọ l’ọba
olúwa, ọlọ́run mi ató bí ju
olúwa, ọlọ́run mi ìwọ l’ọba
olúwa, ọlọ́run mi ató bí ju
olúwa, ọlọ́run mi ìwọ lọba
iwó l’oba, owó l’oba, íwó l’oba
olúwa, ọlọ́run mi ìwọ l’ọba
iwó l’oba o, owó l’oba, íwó ni
olúwa, ọlọ́run mi ìwọ l’ọba
olúwa, ọlọ́run mi ató bí ju
olúwa, ọlọ́run mi ìwọ l’ọba
olúwa, ọlọ́run mi ató bí ju
olúwa, ọlọ́run mi ìwọ l’ọba
Random Lyrics
- veetchy - i.t.m lyrics
- clascyjitto - yeehaw deliveryboy lyrics
- diimalo & mda - autoamor lyrics
- nbhd nick - been had lyrics
- icybando - ic3b3rg lyrics
- feduk - музыка на мне (music on me) lyrics
- acidrxin! - плак (plak) lyrics
- bob that master - tell me why lyrics
- soha (kr) - sweet & sour lyrics
- gallure - spacecraft! lyrics