asake - 2:30 lyrics
[intro]
uh
obah
what dem a say?
obah
run
hmm, hmm, hmm, hmm
hmm, hmm, hmm, hmm
hmm, hmm, hmm, hmm
hmm, hmm, hmm, hmm
[verse 1]
awa de, awa de de
awa lọmọ to n sọ ti o seke, ye
orimọlade gbemi debẹ
jigan jigan
ẹsẹ mi o delẹ, delẹ
alaye mi stop shebẹ
o fẹ jenbi, otun fẹ jenbẹ
opọ se
agbawo, fẹnu fo fence
sun sẹ yin
amọrawa, sho get?
abinibi yato s’ability
ẹsọ fun wọn tan ba teri si
wọn ma pa lori
tẹnu kọ, emi promising
awọn tẹ fọ fun, fọ fun mi
tori ko sẹ lomi
many many fẹ dabi mi
eri bi
ẹgbọlorun tobi
mo da aso+ẹbi for my country
you can call me mr money
[chorus]
hmm, hmm, hmm, hmm
hmm, hmm, hmm, hmm
2:30 fẹlu
oya ka turn up
kilẹ to mọ
hmm, hmm, hmm, hmm
hmm, hmm, hmm, hmm
ye, ye, ye
2:30 fẹlu (thirty fẹlu)
oya ka turn up
kilẹ to mọ
[verse 2]
ere moba wa kosi ja
shokoto pen pe, ye
ayenika, yebo, yeba
formation logba, ye ja
ọmọ’yami ko stay wise
tranquility, tranquility
i no get time to dey form activity
kole kalas, i dey find stability
like abacha, monеy long infinity
what’s the chances?
what’s the probability?
to see a bеtter version of me with agility
no you can’t fake reality
ogun, princ+p+lity and calamity
mo ti lọ, mo ti pa iyen ti
bẹbẹ no de for jiji
o shi wa n titi
still get money like fifty
dripping like fiji
i be real g
[chorus]
hmm, hmm, hmm, hmm
hmm, hmm, hmm, hmm
2:30 fẹlu
oya ka turn up
kilẹ to mọ
hmm, hmm, hmm, hmm
hmm, hmm, hmm, hmm
ye, ye, ye
2:30 fẹlu
oya ka turn up
kilẹ to mọ
Random Lyrics
- bahati - size yangu lyrics
- эндрю рэст (andrew rest) - чинилы (fixers) lyrics
- шоппер (shopper) - туса рая (paradise party) lyrics
- e.v. [lat] - kulturāls fenomens lyrics
- ikd-sj - last / exodus lyrics
- 21 milli - change the story lyrics
- aaron taylor - patience lyrics
- munna duke - off tha porch lyrics
- rolexus - esmu atgriezies lyrics
- יוסי בנאי - shir mishmar - שיר משמר - yossi banai lyrics