balloranking - morayo lyrics
n′orile, òrìn ti dè
ojuelegba, wón má shá’e l′égbá
ni surulere, wón ò nì sùrù
ooh+ooh, ohh
yeah+yeah, you know say na zero pa’
i am balloranking
(sh’+sh′+shakablaka)
verse
ómó, mòyá gb′ónà ti mí mò (ti mí mò)
if sapa dey, i mò pè ò ni bámi ló (ò ni bámi ló)
name any hustler, dey for babylon (for babylon)
if i no make am, tálò fè bámi gbó? (fé bámi gbó?)
mm+sh’òmá jékin mó b′òdé shèè má jé? (shèè má jé?)
mòni sh’òmá pádè mi t′òbá tì d’álé? (′bá tì d’álé?)
shèbì awón paddie mi nì “k’òmá ló béh” (k′òmá ló béh)
jóór, sh′òmá wá pélú mì, bámikálé? (bámikálé)
chorus
ìyì àtì ólá ni mò wá ló, ah (wá ló)
mòti rì’rè, mòr′áyó (r’áyó)
gbèdu gbè dè, kuramo (′ramo)
láilái, t’óbá l′áwón ò dámó? (dámó)
kilòfé fá kárámó? (kárámó)
wón l’áwón ò mó+mó (ò mó+mó)
wón j’ólá muhammād (muhammād)
òyá give dem, jéki wón má sóh n′tón sóh
ayy, ah+ahh
verse
baby, don′t leave me now
dákùn, má dá mi, jóór
you know me sharp shooter, i’ll give you proper now
sweetie love, my dear oh (sweetie love, my dear)
you know say me no there oh (you know say me no there oh)
ìwó l′òlè gbèmi dè’bé oh (dè′bé oh, dè’bé oh)
pretty love, my dеar+eh
verse
girl, you bе my super charger
say if dem try, ómó, na back to sender oh
mmm, baby, make we meet for zanga oh
you know say me and ballo′ give them bangers (mmm)
ómó, baby, májé k’ájá (k’ájá oh)
i go dey give am to you faster+faster (faster+faster oh)
baby+baby, májé k′ájá (májé k′ájá oh)
i go dey give am to you faster+faster (faster+faster)
so, make we link up, link up, link up
sháyò, drink up, drink up, drink up
verse
ómó, mòyá gb’ónà ti mí mò (ti mí mò)
if sapa dey, i mò pè ò ni bámi ló (ò ni bámi ló)
name any hustler, dey for babylon (for babylon)
if i no make am, tálò fè bámi gbó? (fé bámi gbó?)
mm+sh′òmá jékin mó b’òdé shèè má jé? (shèè má jé?)
mòni sh′òmá pádè mi t’òbá tì d′álé? (‘bá tì d’álé?)
shèbì awón paddie mi nì “k′òmá ló béh” (k′òmá ló béh)
jóór, sh’òmá wá pélú mì, bámikálé? (bámikálé)
chorus
ìyì àtì ólá ni mò wá ló, ah (wá ló)
mòti rì′rè, mòr’áyó (r′áyó)
gbèdu gbè dè, kuramo (‘ramo)
láilái, t′óbá l’áwón ò dámó? (dámó)
kilòfé fá kárámó? (kárámó)
wón l’áwón ò mó+mó (ò mó+mó)
wón j′ólá muhammād (muhammād)
òyá give dem, jéki wón má sóh n′tón sóh
ayy, ah+ahh
outro
burst my speaker, gimme your knicker
all on me dancer, or in my nice car?
gimme your knicker, whines ‘pon ni star
only me, dies+ah, bicyclely style (ìyì àtì ólá ni mò wá ló)
gimme distance, don′t let me distant (mòti rì’rè, mòr′áyó)
all of my guys are, p+rnstar, my n+gga (‘mò wá ló)
outro
mòti rì′rè, mòr’áyó
mm+mmm, ólá ni mò wá ló
mòti rì’rè, mòr′áyó
mòr′áyó, yeah+yeah
á ònilè, tòh sááló
ároyé kò ká’gbón
á ònilè, tòh
Random Lyrics
- dj maxzz & dj serial (bra) - montagem vozes profundas 2 (slowed) lyrics
- mc ln - sente o peso lyrics
- tanguy - aujourd'hui lyrics
- mcfds - болеh lyrics
- j.sheon - 囚 (soul away) lyrics
- paulina jayne - after the party's over lyrics
- victor mendivil & dan sanchez - salazar lyrics
- samuray kuba - hellou lyrics
- tired cossack - sleepy beepy lyrics
- пиллснэйшн (pillsnation) - связь (connect) lyrics