banky b - shö tí gbó (street anthem) lyrics
revonoitul is a state of mind…
uhh, omo wetin dey happen for this naija just dey make me laugh…
omandun, fílè fun
sho ti gbo?, listen uh!
śhö tí gbò pe jay z ti turn new leave…
(śhö tí gbò!)
sam loco tíń shè new film,
(śhö tí gbò!)
śhö tí gbò orin jhybo àtí rihanna,
work work remix tàń shè lódòo cabbasa,
śhö tí gbò pe dangote tí broke?
ótíń kiri rice àtí sugar kiri àdùgbò?
(śhö tí gbò!)
śhö tí gbò pè terry g tí dì woli
ótíń wàsù kírí gbògbò lekki ati ikoyi,
(śhö tí gbò!)
śhö tí gbò pè skibii tí resurrect,
davido lòsì bakery ô lòń tòró bread,(uh)
(śhö tí gbò!)
śhö tí gbò pè mr ibu tí ńí six pack,
àbòtí gbò pé tb joshua tí jí 2pac?
(śhö tí gbò!)
śhö tí gbò pè chibok girls tídí òlòshó,
club ní sambisa fùń tàlíkà atí olowo,
(śhö tí gbò!)
shè ígbè èràń lòmàn fí sinu cake ní,
abi otiri abirun tòn double date ní?
fela anikulapo lo ni church wa!
(śhö tí gbò!)
kama muti kama shayo sha ni choice wa!
(śhö tí gbò!)
bill gates, donald trump ti gbè call wa!
(śhö tí gbò!)
eje jesu la fi duro won le fall wa!
(sho ti gbo)
fela anikulapo lo ni church wa!
(śhö tí gbò!)
kama muti kama shayo sha ni choice wa!
(śhö tí gbò!)
bill gates, donald trump ti gbè call wa!
(śhö tí gbò!)
eje jesu la fi duro won le fall wa!
(sho ti gbo)
śhö tí gbò pè small doctor fè gbà grammy,
abi śhö tí gbò pè soyinka shí wàn primary?
śhö tí gbò pè genevieve gan tin fò
funmi? òrín tí mòń kóyí drake lō koò funmi,
śhö tí gbò pè pasuma shè jimmy jump
off, àbò tírí pastor tòn shé skibijobor?
beyoncé wà toast mi for where i dey,
àbò tigbò zone out session sunny ade?
śhö tí gbò pè awilo shè cover panda?
kilan fani afoju tokun powder,
(uhh)
èwùrè tòfè pà lion,
majid michel ninu film mount zion,
. shey you hear say jesus christ no go come again?
tòrí pè lucifer tídi born again,
shatta bandle get money pass bill gate?
śhö tí gbò pè ómo celè ní lil wayne!
fela anikulapo lo ni church wa!
(śhö tí gbò!)
kama muti kama shayo sha ni choice wa!
(śhö tí gbò!)
bill gates, donald trump ti gbè call wa!
eje jesu la fi duro, won le fall wa
(śhö tí gbò!)
fela anikulapo lo ni church wa!
(śhö tí gbò!)
kama muti kama shayo sha ni choice wa!
(śhö tí gbò!)
bill gates, donald trump ti gbè call wa!
(śhö tí gbò!)
eje jesu la fi duro won le call wa
sho ti gbo!
śhö tí gbò pè omo ibadan ni eminem,
abo tigbo pe naira marley feje president?
śhö tí gbò pè olamide tín wà uber?
abò tí gbò pè don jazzy tín ta suya?
shey you don’t hear say my mama na virgin?
abò tíri òmò president tòn kíri breadí?
ení tàye ńshè tòfè màlò phensic? pastor adebayo, oyedepo lò betting,
śhö tí gbò pè bariga lo’tedola ngbè? adenuga lòbí mí sùgbòn mò sànlè,
śhö tí gbò pè pastor chris lòní quilox?
wasiu ayinde gàań fè feature rick ross,
shey you don’t hear say buhari don bring change?
you wàn feature wizkid with only 2k?
śhö tí gbò pè agbero ní broda sh+ggi,
make una forget say na me be banky!
repeat chorus.
òtí yè eh, mafo fùn anybody, tori eni tan fofun kotu gbodo mafo,
eni tan fofun toba tin fo, oti n ‘f up niyen,
omo iya mi, śhö tí gbò!
omandun!
banky b!
Random Lyrics
- love ghost - beautiful crime lyrics
- sevn alias - regendruppels lyrics
- the nude party - thirsty drinking blues lyrics
- la herencia - y te vi con el lyrics
- selena gomez - lose you to love me (demo version) lyrics
- grupo bandy2 - ya me cansé lyrics
- yaroscar - l'écho lyrics
- nepumuk - weltlauf lyrics
- brasa church - fiel lyrics
- engine kid - windshield lyrics