azlyrics.biz
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

bantu (crew) - jagun jagun lyrics

Loading...

[chorus]
jagun+jagun ló ń bọ̀
jagun+jagun ló ń bọ̀
jagun+jagun ló ń bọ̀

[verse 1: chant]
olórí+ogun ò gbọdọ̀ kẹ́yìn ogun
ọ̀kan ṣoṣo ẹja tí ń d’abú+omi rú
ọ̀kan ṣoṣo ẹfọ̀n tí ń d’ọ̀dàn rú
ọ̀kan ṣoṣo àjànàkú tí ń m’igbó kìji+kìji
jagun+jagun dé, ọmọ ọba kìí jagun bí ẹrú
òlọ́ṣọmọ́dìí gba ìbọn lọ́wọ́ ọmọ ojo
jagun+jagun, afiwájúgbọta, afẹ̀yìngbọfà
jagun+jagun ò fẹ́rọ̀, alágbára èyàn tí ń fi májèlé ròfọ́
àlùjànú èyàn tí ń fi ọmọ+odó tayín
bó ṣe ń bá ọmọdé ṣe, bẹ́ẹ̀ ló ń bágbà ṣe
kọ̀nàn+kọ̀nàn já tòun tòwú
jagun+aso, ẹkùn ọkọ òkè!
arọnimaja ṣáagun!
ó ṣáagun ṣáagun, ó ṣáagun títí, ohun l’awo alágbàá`a, èyí tí ó fi ta b’aṣeégún lójú

[chorus]
jagun+jagun ló ń bọ̀
jagun+jagun ló ń bọ̀
jagun+jagun ló ń bọ̀



Random Lyrics

HOT LYRICS

Loading...