barry jhay - see me see god (smsg) lyrics
[intro: chief dr. sikiru ayinde barrister (mfr) & barry jhay]
ẹ maa ka mi mọ wọn, ṣe ni mo da duro
ọrọ mi d’akọ alangba, ko ṣe jẹ ni tutu
koda, ko ṣe china t’ọn gbe ti n jẹ wọn
ẹni j’alangba n tutu, a kó warapa
oh+ah, oh+ah+ah+ah
yeah, ay+ya+ay, ah+ah, ah
oh+wa, oh, wa+wa+wa
(n0body’s perfect)
[verse 1]
yea, k’iku ma+ma pa awọn to gbe mi s’ori bi gele
ki ibanujẹ jina si wa rere, tefe+tefe
k’iku ma p’ọta mi, ko le r’iran wo
(o ri mo fa to n jo, and they no fit hold me, different effect, ah)
ki’ku ma p’ọta mi, ko le r’iran wo
(mo ṣi n m’ẹyẹ bọ lapo, jẹ gbese lapo, ọta mi lo n jẹ gbese, mo mọwọ na)
[pre+chorus]
if i see say wahala don dey too much, na to roll up a big fat one
motivation gan ti n pa’yan, wahala nikan kọ o
ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ (ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ)
[chorus]
see me, see god o, abi emi naa kọ
ọmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy, yeah+yeah
ṣe you dey see level o?
barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yеah, tẹti mọ ọ, ye
[verse 2]
ye, as i dey find wеtin i go chop, ooh+iy
make i no jam wetin go chop me
olúwa lo gbe (yea+yea), lo gbe mi s’oke
emi ko le ṣ’ai ṣope
[chorus]
see me, see god o, abi emi naa kọ
ọmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy, yeah+yeah
ṣe you dey see level o? (ṣe you dey see level o?)
barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yeah, tẹti mọ ọ (yeah)
yeah, o l’oju ọmọ to damọ
[pre+chorus]
if i see say wahala don dey too much, na to roll up a big fat one
motivation gan ti n pa’yan, wahala nikan kọ o
ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ (ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ)
[chorus]
see me, see god o, abi emi naa kọ
ọmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy, yeah+yeah
ṣe you dey see level o? (ṣe you dey see level o?)
barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yeah, tẹti mọ ọ (yeah)
yeah, o l’oju ọmọ to damọ
[outro]
sunshine
Random Lyrics
- jane powell - i got it bad and that ain't good lyrics
- abtin - take you away lyrics
- cashman, pistilli & west - red is red lyrics
- hu? (est) - ebanormaalne lyrics
- lepers - void lyrics
- miracle mangal & ybn supari - 0n my 0wn lyrics
- cutlass - tear lyrics
- 18 bonez - 720 lyrics
- edwin leal - last time lyrics
- tha (thampl9) - your lie in april lyrics