brymo - alelúyà méje lyrics
aleluya meje meje
oselu pejo fun ojo meje
won fe to’lu lojo meje
gbogbo isele korin kese
aleluya meje meje
awon ojelu fere ge
won l’awon omo epa tun tide
won fe darulu mere le
aleluya meje meje
akoni leru won tun ti de
won fe so bose mama gbe
iwo n foku sorun o n sise agbе
gbogbo isele korin kesе
won l’awon omidan lo maye le
won fe jeka won fe roso
oko loma ye okunrin le
bo kowaju si e kota
boba keyin si e kota
boba kuwo nikan se hun o le se
ma gbagbe ibi o ti babo
bo kowaju si e kota
boba keyin si e kota
boba kuwo nikan se hun o le se
ma gbagbe ibi o ti babo
aleluya meje meje (arere epa epa)
adaleru won tun ti de (arere epa epa)
ko fe k’omo o mo baba re (arere epa epa)
ko fe k’oko ko gbo t’aya re (arere epa epa)
gbogbo isele korin kese (arere epa epa)
won l’awon omidan lo maye le (arere epa epa)
won fe jeka won fe roso (arere epa epa)
oko loma ye okunrin le (arere epa epa)
Random Lyrics
- don diablo - invisible lyrics
- rjldiablo - mega lyrics
- gravewalker - hellknight lyrics
- landless - heavy lyrics
- sad barttt - somyeah lyrics
- helixson - cancer with a pearl lyrics
- jhoanda lyrics lyrics
- finn play - ทำเพลง trap ใน 3 นาที (make trap song in 3 minutes) lyrics
- jonatha brooke - taste of danger (2020) lyrics
- ths - laapata lyrics