azlyrics.biz
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

brymo - ba nu so lyrics

Loading...

[verse 1]
abéré á lo
abéré á lo
k’ó nà okùn ó tó dí ò
a ò ní dé bá won
a ò ní dé bá won
ení bá ní a máà de ò

[hook/chorus]
bá’núso
bá’núso
má b’enìyan só
bá’núso
bá’núso
má b’enìyan só

[verse 2]
omijé á gbe
omijé á gbe
ìbànújé á dèrin ò
eniafé
eniafé lamò o
a ò mo’ni tó fé ni ò

[hook/chorus]
bá’núso
bá’núso
má b’enìyan só
bá’núso
bá’núso
má b’enìyan só
[verse 3]
ení bá ma b’ésù jeun
síbíi rè á gùn gan
eni ò mò wáwù
óma tee
òsèlú mà ló layé ò

[hook/chorus]
bá’núso
bá’núso
má b’enìyan só
bá’núso
bá’núso
má b’enìyan só

[verse 4]
èyin ará
ewá gbó òò
òrò kan se ùrùn ùrùn nínú iii
sé kín só
kín só
ká bá’núso

[hook/chorus/outro]
bá’núso
n’òní b’enìyan só
bá’núso
bá’núso
má b’enìyan só
bá’núso
bá’núso
má b’enìyan só



Random Lyrics

HOT LYRICS

Loading...