azlyrics.biz
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

brymo - òrun n móoru lyrics

Loading...

teti ko gbo
ile oba ti gbanna
awon ijoye won ni kosowo lowo oba
won soro e leyin
olori lo n rofo l’oba n san ra

orun n mooru
orun n mooru
eni lo lomo
eni bo lomo

instrumental playing

oba o gbepo pari, ko binu
o ni kiwon pade ohun laafin
awon ijoye won tiju bonba r’oba
won soro e leyin
olori lo n roka l’oba n san ra

orun n mooru
orun n mooru
eni lo lomo
eni bo lomo

orun n mooru
orun n mooru
eni lo lomo
eni bo lomo



Random Lyrics

HOT LYRICS

Loading...