azlyrics.biz
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

congress musicfactory - a gbéeyín ga lyrics

Loading...

a gbéeyín ga

[ẹsẹ]
oluwa oun gbogbo
alagbara
oba awon oba
ko s’eni bi re

aseyi o’un
olododo
oluwa mimo
ko s’eni bi re

[pre-akorin 1]
a gbe oruko yin ga
eyin ni iyin at’ogo ye
ni isokan
agb’owo soke

[akorin 1]
gbe yin ga
a gbe oruko yin ga
oluwa a yin o logo
af’ogo fun yin

gbe yin ga
a gbe oruko yin ga
oluwa a yin o logo
a ngbe lati yin yin

[ẹsẹ]
oluwa oun gbogbo
alagbara
oba awon oba
ko s’eni bi re

aseyi o’un
olododo
oluwa mimo
ko s’eni bi re

[pre-akorin 2]
olorun olot-to
ti wa pelu wa ni irin ajo yi
ni isokan
agb’oun soke

[akorin 2]
gbe yin ga
a gbe oruko yin ga
oluwa a yin o logo
af’ogo fun yin

gbe yin ga
a gbe oruko yin ga
oluwa a yin o logo
t-ti aiye

[akorin 3]
a gbe yin ga
a gbe oruko yin ga
oluwa a yin o logo
af’ogo fun yin

gbe yin ga
a gbe oruko yin ga
oluwa a yin o logo
a ngbe lati yin yin
a ngbe lati yin yin



Random Lyrics

HOT LYRICS

Loading...