congress musicfactory - sí o lyrics
sí o
[ẹsẹ]
a gboju s’oke (okurin)
a gbowo s’oke (obirin)
a gbo’un soke ni iyin yin (ifohun sokan)
ife wa fun o (okunrin)
sii o (obirin)
okun wa fun o (okunrin)
sii o (obirin)
a f’aye wa fun ijosin yin (ifohun sokan)
[akorin]
sii o (obirin) [sii o (okunrin)]
sii o (obirin) [iwo nikan (okunrin)]
a fi isin wa (ifohun sokan)
gbogbo iyin wa
sii o
sii o (okunrin) [sii o (obirin)]]
sii o (okunrin) [iwo nikan (obirin)]
a fi isin wa (ifohun sokan)
gbogbo iyin wa
sii o
[ẹsẹ]
a gboju soke (obirin)
sii o (okunrin)
a gbowo soke (obirin)
sii o (okunrin)
a gbo’un s’oke ni iyin yin (ifohun sokan)
ife wa fun o (okurin)
sii o (obirin)
okun wa fun o (okurin)
sii o (obirin)
af’aye wa fun ijosin yin (ifohun sokan)
[akorin}
sii o (obirin) [sii o (okunrin)]
sii o (obirin) [iwo nikan (okunrin)]
a fi isin wa (ifohun sokan)
gbogbo iyin wa
sii o
sii o (okunrin)
[sii o (obirin)]
sii o (okunrin) [iwo nikan (obirin)]
a fi isin wa (ifohun sokan)
gbogbo iyin wa
sii o
[àdúrà]
mo bùkún fún o, mo bùkún fún o, mo gbé owó mi sókè sí ìté àti síwájú re. mo gbé okàn mi wá síwájú orúko mímó re. láti inú ayé mi àwon ohun mímó ndìde g’òkè sí olórun. láti inú ayé mi àwon ore mímó nsàn g’òkè sí o
mo gbé àwon ìrúbo opé, àwon èso enu mi nse ìdupé sí orúko re
mo wá sìwàjù re, mo sì mú ore mi wá fún o
[akorin]
sii o (harmony) [sii o (okunrin)]
sii o (harmony) [iwo nikan (okunrin)]
a fi isin wa (ifohun sokan)
gbogbo iyin wa
sii o
sii o (okunrin) [sii o (obirin)]
sii o (okunrin) [iwo nikan (obirin)]
a fi isin wa (ifohun sokan)
gbogbo iyin wa
sii o
[ipari]
a fi isin wa
gbogbo iyin wa
sii o
a fi isin wa
gbogbo iyin wa
sii o
a fi isin wa
gbogbo iyin wa
sii o
a fi isin wa
gbogbo iyin wa
sii o
a fi isin wa
gbogbo iyin wa
sii o
a fi isin wa
gbogbo iyin wa
sii o
Random Lyrics
- christina milian - virginity lyrics
- chuxx - so good lyrics
- jay-r - boo lyrics
- hillsong global project - eterno amor lyrics
- strombers - el coche de manolo lyrics
- depedro - la llorona lyrics
- trapo - hello lyrics
- don sensezi - lambo nomics part 2 lyrics
- reverend horton heat - beer holder lyrics
- seas on the moon - hovering lyrics