d fada - journey lyrics
Loading...
ẹjẹwọ, ẹ má pa mi
gbogbo òṣì tí ẹ sọ yẹn kọ′mátà ni
lo ṣe jẹ’ kín face bukata mi
tọmọde àti àgbà ló like pattern mi
ó sure pé wọ′n má gbe wa
ó sure pé mà ri rábà mi
mo jáde tán mo buckle sanda mi
ẹlédà kò gbà mí
bad energy ké yà kò gbà yín, ké yà kò gbà yín
the journey far
mò ń lọ ibi gíga
i be hustler, kí n má rí gbà
mo kan rí pé mo jẹ’ lọ́, ǎánú nì mo rí gbà
this music thing i too sabi
mà fi ọmọ wé ọmọ, kò lè dàbí
ṣọ’rẹ′ ṣọ′rẹ’ màmá rí gbà ní
à máa rí gbà ní
wọn jámi, emi ní mo járami
owó tí mo ní, ní mo ya ara mi
several times tí mo ṣùkùn nínú yàrá mi
look at me now ẹ′yin ara mi
ọmọolórè wọn lè gba kádàrá mi
ọmọolórè ò ní mofò
when there is no money kíní kókó
ẹlẹ’nù pèlẹ′bẹ’ olófofò
pẹ′lú gbogbo tì ẹ sọ, kíní kókó
kíní kókó
Random Lyrics
- silent_masonwolf - five nights of agony lyrics
- nora aunor - white christmas lyrics
- alouest (esp) - 6 llamadas lyrics
- deadmicah - follow the leader lyrics
- tony chasseur & chyco siméon - fanm mizik (30 ans) lyrics
- spongebob schwammkopf - bell' mal wau lyrics
- spello - illusion lyrics
- arda keskinçelik - gizli (freestyle) lyrics
- ame (phl) - atensyon lyrics
- lemon power - i'm an animal lyrics