emmy_tee - aworan ife lyrics
bọtá fẹ sọrọ,kọ sọrọ kọ sọrọ ọ
bọbá má binu, kọ binu o o
bọbá má párá won láyo jẹ o o, fáworan ifẹ ẹ mi
bọtá fẹ sọrọ,kọ sọrọ kọ sọrọ ọ
bọbá má binu, kọ binu o o
bọbá má párá won láyo jẹ o o, fáworan ifẹ ẹ mi
aworan ifẹẹẹẹ, ẹ ẹ ẹ ẹ
aworan ifẹẹẹẹ, ẹ ẹ ẹ ẹ, girl yea
aworan ifẹ,girl your picture′s painted in my heart and it’s so beautiful
so omoge can you see, hope you feeling me
like i′m feeling you and you’ll be loving me
like i’m loving you too bae ay ay o
awele wákájo, ijo tiyá ko bọságbo
you want to do,baby make we go
i no go rush, i go take it slow o
páreke e e, páreke fáwele o
páreke fáwele mi le le le eh
awele wákájo, ijo tiyá ko bọságbo
you want to do,baby make we go
i no go rush, i go take it slow o
páreke e e, páreke fawele o
páreke fawele mi le le le eh
bọtá fẹ sọrọ,kọ sọrọ kọ sọrọ ọ
bọbá má binu, kọ binu o o
bọbá má párá won láyo je o o, fáworan ifẹ ẹ mi
bọtá fẹ sọrọ,kọ sọrọ kọ sọrọ ọ
bọbá má binu, kọ binu o o
bọbá má párá won láyo je o o, fáworan ifẹ ẹ mi
aworan ifẹẹẹẹ, ẹ ẹ ẹ ẹ
aworan ifẹẹẹẹ, ẹ ẹ ẹ ẹ, girl yea
say baby come o,omo wa kásere
look into my eyes baby what i feel is true
omo this your love won make me kolo eh
dey make me think of you everyday
awele wákájo, ijo tiyá ko bọságbo
you want to do,baby make we go
i no go rush, i go take it slow o
páreke e e, páreke fáwele o
páreke fáwele mi le le le eh
awele wákájo, ijo tiyá ko bọságbo
you want to do,baby make we go
i no go rush, i go take it slow o
páreke e e, páreke fawele o
páreke fawele mi le le le eh
bọtá fẹ sọrọ,kọ sọrọ kọ sọrọ ọ
bọbá má binu, kọ binu o o
bọbá má párá won láyo je o o, fáworan ifẹ ẹ mi
Random Lyrics
- ярмак (yarmak) - моя країна lyrics
- run deliks - hmu lyrics
- ヘラヘラ三銃士 (herahera-sanjyushi) - 花火 (hanabi) lyrics
- ykk - whatthefu? lyrics
- bri bagwell - old together lyrics
- joe tex - detroit city lyrics
- adrian sky - lucky lyrics
- keanu bedd - teen suicide lyrics
- lov (fr) - osp lyrics
- emdivity - душевна па-дамашнєму (soul pa-damashnu) lyrics