evang. dare melody - jiji mo ji lyrics
olurun gbami, eleda mi faye gba mi o, mo fe wonu ogo mi lo
oshi o ye mi, lodun mo was a yi(lodun ti mo wa yi ori buruku oye mi)
ko ye ki babami o ji ya, kemi omo o tun bere.
dide se iyanu lakoko
oluorun gbami.
sebi iwo lolorun to gbo ti danieli lojo yen.
ma sayi wa gbohun ebe mi
oluwa dide ninu agbara re ko wa jewo agbara re
atipe iwo loba to ni kin ma beru, pe oni fimi fun iya je.
kilowade, ko ye ki omo alaso mi ko ma wo akisa, ko. ma de ye komo alapata mi, kowa je egungun eran
olorun mi
so de di igba ti transportation wa jemi ni iya
kin to de ile re olorun mi.
baba tete wa bamise
ani bi mo ba pe o lekan, sa ma je mi ni igbeje gbejo
oluwa o
oluorun gbona ara kowa se iyanu laye mi o
lasiko yi o olorun mi o
ire ati anu re ko ma tele mi lo.
jiji moji saye, mo kunle mo…
Random Lyrics
- jesus cifuentes & la cantaña sound - días de colores lyrics
- curselife - devious lyrics
- $treble x jde - stress relief lyrics
- ryan adams - stop you lyrics
- مشاري العوضي - qesah lyrics
- tha k-man - spanish butterfly lyrics
- diacero - sin huellas lyrics
- grupo jalado - un día más sin tu amor lyrics
- lauren alaina - think outside the boy lyrics
- niki tall - joy lyrics