
halfolabi - ko wami wale lyrics
ko wa mi wale o /2xe
ire owo o, ire omo o,ko wa mi wale /2xe
ko bami nile o /2xe
ire owo o, ire omo o, ko bami nile /2xe
owo oluwa, o n be laye mi o
ife oluwa, o n be laye mi o
mo ri, mo ri, mo ri, mo ri aanu gba
owo oluwa, o n be laye mi o
ife oluwa, o n be laye mi o
mo ri, mo ri, mo ri, mo ri aanu gba /2xe
ire owo o, ire omo o, ko wa mi wale
ire owo o, ire omo o, ko bami nile
owo oluwa, o n be laye mi o
ife oluwa, o n be laye mi o
mo ri, mo ri, mo ri, mo ri aanu gba /2xe
baba mimo ti fun mi layo o, ire /4xe
baba ogo mure aye mi wa/ 2xe
orisun ayo mi, maje ko gbe / 2xe o o o e e e
baba ogo mure aye mi wa
orisun ayo mi, maje ko gbe / 3xe
baba ogo mure aye mi wa /2xe
orisun ayo mi, maje ko gbe / 2xe
baba ogo mure aye mi wa
orisun ayo mi, maje ko gbe / 3xe
mo ri , mo ri , mo ri, mo ri’yanu gba /8xe
mo ri , mo ri ,mo ri, mo ri ri’yanu gba
baba nawo nawo, nawo agbara re o, nawo agbara re o
sese, sese ninu aye, ninu aye mi o baba
wonu , wonu, wonu agbara , wonu agbara lo baba
baba nawo nawo, nawo agbara re o, nawo agbara re o
sese, sese ninu aye, ninu aye mi o baba
wonu, wonu, wonu agbara, wonu agbara lo baba
baba nawo nawo, nawo agbara re o, nawo agbara re o
sese, sese ninu aye, ninu aye mi o baba
wonu, wonu, wonu agbara, wonu agbara lo baba
open the door to my blessings, to my blessings /2xe
oh oh /2xe to my blessings
ah ah /2xe to my blessings
oh oh /2xe to my blessings
show me the way to my blessings, to my blessings
open the door to my blessings, to my blessings /3xe
show me the way to my blessings, to my blessings /2xe
open the door to my blessings, to my blessings /3xe
ah ah /2xe
oh oh /2xe
owo owo agbara, o n be lara mi o
owo oluwa, o n be lara mi o
owo owo agbara, o n be lara mi o
owo oluwa, o n be laye mi o
owo oluwa, o ti tumi sile
nawo agbara re, sinu aye mi o
baba o, onile ayo
iwo ma lo ni majemu ogo
iwo ma lo ni majemu ayo
nawo agbara re, sinu aye mi o
iwo ma lo ni majemu ogo
iwo ma lo ni majemu ayo
baba o, baba o/ 2xe
baba o, nawo agbara re /2xe
baba o, fi titobi han / 4xe
baba o, nawo agbara re /2xe
Random Lyrics
- bitză - intro (sevraj) lyrics
- muwral - почерк (handwriting) lyrics
- cortex - pourquoi lyrics
- lille caesar - kanke få alt lyrics
- рома факти (roma fakty) - лазери з очей (lasers from the eyes) lyrics
- tedra 220 - todo pasará lyrics
- care bears - i really love tacos lyrics
- metrotone - put it on black lyrics
- whycinko - poison lyrics
- falcko - error 500 b lyrics