azlyrics.biz
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

hibeekay - ojo ayo mimo lyrics

Loading...

ojo ayo mimo oni soju mi
mo yo mo dupe, mo yin jesu logo
ki gbogbo araye ba mi gbohun soke
si metalokan mimo to n sise ara gbangba
emi a jo ma kawo mi soke genge
mo jo mo yo, mo yin oluwa
ore ti jesu se fun mi po jojo o
ewa ba mi sopo ijo, aleluya

1). bi emi ba legberun ahon lati yin o
ko ma ma toooo, fun ore oluwa
tori ife re laye mi o ma po gan o
dansaki re o baba mi, jowo gbope mi
olorun to fi idi aye sole, mo gbe o ga
osuba re reeee, mo fiyin fun o
kabiyesi to ti wa kaye to wa jowo gba iyin mi
iba re o baba mi, oluranlowo mi
chorus: ojo ayo mimo oni soju mi
mo yo mo dupe, mo yin jesu logo
ki gbogbo araye ba mi gbohun soke
si metalokan mimo to n sise ara gbangba
emi a jo ma kawo mi soke genge
mo jo mo yo, mo yin oluwa
ore ti jesu se fun mi po jojo o
ewa ba mi sopo ijo, aleluya

2). a da ri gbogbo ogo pada sodo rе baba mi
iwo lo niiii, enikeni ko le ba o pin
tori orе ofe nla ni fun wa ta fi ri ojo oni o
awa laye, awa laye, atun wa laye wa
ti nbani kin ka ore oluwa lati ibere aye mi
ile a suuuu, osu a tan odun a koja
si be mi o tun le ka tan ti nbani kin ka lokankan
tori ore oluwa laye mi akaikatan ni

chorus: ojo ayo mimo oni soju mi
mo yo mo dupe, mo yin jesu logo
ki gbogbo araye ba mi gbohun soke
si metalokan mimo to n sise ara gbangba
emi a jo ma kawo mi soke genge
mo jo mo yo, mo yin oluwa
ore ti jesu se fun mi po jojo o
ewa ba mi sopo ijo, aleluya
bridge: ore t’oluwa se fun mi
opor gan gan o
anu re laye mi
oju nipa ise mi lo
owo agbara re laye mi
o koja imo mi
ose o ose o ore re po gangan
agbanilatan o ife re po gangan
ogbeni nija keru o bonija agbara re po gangan
oba tin gba alailara anu re po gangan
ose o ose o ore re po gangan



Random Lyrics

HOT LYRICS

Loading...