ibrahim maalouf & angélique kidjo - eyin lyrics
solomoni ti won so foun mi, m’kpé oti yan
o jisè rè l’aarin awon èyè
solomoni ti won so foun mi, m’kpé oti yan
o farè ofin ati ogbon si won léri
shugbon ojé ajeji èyè kan, nin emi lati soro si o
sibé ni èyè ti èmon rara ni min lati soro si nin sin
shugbon ojé ajeji èyè kan, nin emi lati soro si o
oro èyè ti èmon rara èyè igolu
eyè yi koni èran
eyè yi koni èjè
eyè yi koni iyè
awo rè ni wipè, èwa goolu
eyè yi olé wa ku
eyè yi olè wa l’ayé
eyè yi ko yéra
ni ibààlè ati doundoun miliki
biribiri rè pipè, to dabi ilé ayé
biribiri rè pipè, to dabi ilé ayé
biribiri rè pipè, to dabi ilé ayé
biribiri rè pipè, to dabi ilé ayé
solomoni, won so foun mi kpé, ègbadoun orin
égbadoun awon orin alapandédé
solomoni, won so foun mi kpé, ègbadoun orin
n’tori ojé adjéji èyè kan ni emi la ti soro si o
shugbon ojé adjéji èyè kan ni emi la ti soro si o
sibé ni èyè ti eèmon rara ni mon lati soro si nin sin
shugbon ojé adjéji èyè kan ni emi la ti soro si o
oro èyè ti èmon rara èyè igolu
eyè yi koni èran
eyè yi koni èjè
eyè yi koni iyè
awo rè ni wipè, èwa goolu
eyè yi olé wa ku
eyè yi olè wa l’ayé
eyè yi ko yéra
ni ibààlè ati doundoun miliki
eyè yi koni èran
eyè yi koni èjè
eyè yi koni iyè
awo rè ni wipè, èwa goolu
eyè yi olé wa ku
eyè yi olè wa l’ayé
eyè yi ko yéra
ni ibààlè ati doundoun miliki
biribiri nin pipè, to dabi ilé ayé
biribiri nin pipè, to dabi ilé ayé
biribiri nin pipè, to dabi ilé ayé
biribiri nin pipè, to dabi ilé ayé
Random Lyrics
- koukr - sin city lyrics
- dj jimmy jatt - warning lyrics
- shawn austin - slip lyrics
- לירון אנג'ל - ad elai - עד אליי - liron angel lyrics
- fern maddie - catherine wheel lyrics
- aquakey - мир мрака (world of darkness) lyrics
- syptember33 & neymo - crash lyrics
- petunia & the vipers - we did not see the light of day lyrics
- tiroteo escolar - core lyrics
- emo grae - life of sin lyrics