ibrahim maalouf & angélique kidjo - obinrin lyrics
méjé, mèsan, méji, ọkan, méjé, duro
méjé, mèsan, méji, ọkan, mèsan bèrè
méjé, mèsan, méji, ọkan, méjèji won foun oti
shugbon ọkan lo moun ti
« makéda »
bayi ni baba mi akebo man kpé min
“balqis”
ni igbami won man kpé min
« makéda »
bayi ni baba mi akebo man kpé min
“balqis”
ni igbami won man kpé min
èmi ni olori ti guusu, guusu, guusu
emi ni olori…
sheeba, sheeba, sheeba
èmi ni olori ti guusu, guusu, guusu
emi ni olori…
sheeba, sheeba, sheeba !
ti wonti so m’kpé oju mijè dudu bi éshuro
ara mi man dan bi okuta iyèbiyè dudu
iyèbiyè dudu
ṣhugbọn kojè ki ayé té min, komanjè iya l’odjodjumon
ti obi min omon aladé
omon aladé
l’akọkọ obinrin ni min
ti wonti so m’kpè emi nin fuyè bi afèfè
ara mi ro bi ara igala
bi ara igala
shugbon ni gbogbo oshè mérin irora kan ma yangbé mi
n’tori ènin èyin è fè ran mi rara
è fè ran mi rara
ki lo djè m’kpè èkpé min nin ayimon?
méjé, mèsan, méji, ọkan, méjé, duro
méjé, mèsan, méji, ọkan, mèsan bèrè
méjé, mèsan, méji, ọkan, méjèji won foun oti
shugbon ọkan lo moun ti
“axoum”
ni oruko ilou ti won bi mi
“méroé”
lori a mimọ èrèkusu ti nile
“axoum”
ni oruko ilou ti won bi mi
“méroé”
lori a mimọ èrèkusu ti nile
èmi ni olori ti guusu, guusu, guusu
emi ni olori…
sheeba, sheeba, sheeba
èmi ni olori ti guusu, guusu, guusu
emi ni olori…
sheeba, sheeba, sheeba !
ti won so m’kpé èrin mi kpashè awon sèhin
kpè guiguisè mi ni irinkérindo to dara
to dara
shugbon nigbati n’wa bi ọmon mon wa jiya gan
n’tori kini èsso m’kpé abuku min ni
abuku min ni
boya ti mon pèja, mon ni lati gba iya
ti won so m’kpé awon jufu mi, adun dudu ni wo fitché
won so wi kpé awon akpo temin won koun kpelou
ara dragoni, ara dragoni
titi nan nin won ko n’kpé èmin oni kpashè
n’tori m’kpé obirin koni ọtoun oro sisso
oro sisso
boya ninou ikpa yara
méjé, mèsan, méji, ọkan méjé, duro
méjé, mèsan, méji, ọkan mèsan bèrè
méjé, mèsan, méji, ọkan méjèji won foun oti
shugbon ọkan lo moun ti
mon béré yin oba solomoni
ta lowa lèyin ohun olusin ?
mon béré yin oba solomoni
ta lowa lèyin ohun olusin ?
méjé, mèsan, méji, ọkan l’ ojo meje ni eje wa duro
méjé, mèsan, méji, ọkan
oshu kesan ni aman duro bi omon
méjé, mèsan, méji, ọkan
omou meji o n’foun ni amoun
méjé, mèsan, méji, ọkan
omo ti oni ongbé!
“makeda”
bẹẹni, emi nin ohun olusin
“balqis”
emi ni obirin ayeraye
“makeda”
bẹẹni, emi nin ohun olusin
“balqis”
emi ni obirin ayeraye
èmi ni olori ti guusu, guusu, guusu
emi ni olori…
sheeba, sheeba, sheeba
èmi ni olori ti guusu, guusu, guusu
emi ni olori…
sheeba, sheeba, sheeba !
Random Lyrics
- alec shaw - mark loops lyrics
- niquice killa rapper - sinto a tua falta (part. eliana matusse) lyrics
- 9ice - election time lyrics
- tate mcrae - she’s all i wanna be (vevo live performance) lyrics
- 2rari - da bambini lyrics
- drue - dig my grave lyrics
- s4brina - naugthy lyrics
- rosie - something i hate lyrics
- lalcko - raw lyrics
- frith hilton - flutter lyrics