ife ogunwumiju - ewure lyrics
oni ka lu ku
jeje eru re
eru re
onikalu ku
jeje agun tan
agun tan
oluronbi jeje omo re
omo re
a pon bi epo
oluronbi o
jo jo
iroko jo jo
oni ka lu ku
jeje eru re
eru re
onikalu ku
jeje agun tan
agun tan
oluronbi jeje omo re
omo re
a pon bi epo
oluronbi o
jo jo
iroko jo jo
jolojolo
jojo iroko jojo
jolojolo
jojo iroko jojo
jolojolo
jojo iroko jojo
jolojolo
jojo iroko jojo
alu jan jan ki jan
iya iya de kun de le
alu jan jan ki jan
gbo ara ye pa yeye re je
alu jan jan ki jan
ij+pa gbe ti e o do run
alu jan jan ki jan
iya iya de kun de le
alu jan jan ki jan
gbo ara ye pa yeye re je
alu jan jan ki jan
ij+pa gbe ti e o do run
alu jan jan ki jan
alu jan jan ki jan
alu jan jan ki jan
alu jan jan ki jan
alu jan jan ki jan
ah ah
eh
eru oba ni moba oba to
eru oba ni moba oba to
oba to
eh
eh
hmm hmm hmm
babalawo mo wa bebe
alugbinrin
babalawo mo wa bebe
alugbinrin
oni n mama mowo be nu
alugbinrin
oni n mama fese be nu
alugbinrin
mo bo ju wo le
momu be nu
alugbinrin
babalawo mo wa bebe
alugbinrin
babalawo mo wa bebe
alugbinrin
babalawo mo wa bebe
alugbinrin
uh uh uh uh
alugbinrin
eh eh eh eh
alugbinrin
alugbinrin
alugbinrin
ye e ye ye ye
alugbinrin
ah ah ah ah
alugbinrin
alugbinrin
ah ah
alugbinrin
hmmm hmmm hmmmm
hmmmm
Random Lyrics
- matoma & astrid s - running out (throttle & niko the kid remix) lyrics
- dev blair - mixter krab$ lyrics
- marié digby - loving you lyrics
- alextbh - between lyrics
- tęskno - pierwsza lyrics
- equipment - phone calls at 3 am lyrics
- erick branco - tente entender lyrics
- the motive (band) - rush lyrics
- $hunmillion$ - indie queen lyrics
- soppgirobygget - sicko mode 2020 lyrics