jaymikee - okun ja lyrics
intro
a lami okun ja!
nipa eje re
a lami okun ja!
bridge
esu daran, esu daran, esu gbe o
esu daran, esu gbe o
esu daran, esu daran, esu gbe o
esu daran, esu gbe o
chorus
a lami okun ja, nipa eje re
a lami okun ja!
a lami okun ja, nipa eje re
a lami okun ja!
verse 1 [joshua israel]
ina nla l’olurun mi o
ina nla, ina nla
eni ba f’owo pada ogun
odi dan dan a gb’ogun lo
ina nla l’olurun mi o
ina nla, ina nla
eni ba f’owo pada ogun
odi dan dan a gb’ogun lo
pre chorus
afeyika iji
omi agbenilo
ojo bale wara wara
jesu ina ajonirun
afeyika iji
omi agbenilo
ojo bale wara wara
jesu ina ajonirun
chorus
a lami okun ja, nipa eje re
a lami okun ja!
a lami okun ja, nipa eje re
a lami okun ja!
verse 2 [ dasola akinbule ]
eni nla l’olurun mi
eni nla, eni nla
olugbeja omo okuro
o be pelumi bi akani eleru
awon to le pa mi
awon ton tеle mi
won o kose won ki o bori
rara o
eni ti o joko sori etе
o fi won rerin eleya
pre chorus
afeyika iji
omi agbenilo
ojo bale wara wara
jesu ina ajonirun
afeyika iji
omi agbenilo
ojo bale wara wara
jesu ina ajonirun
chorus
a lami okun ja, nipa eje re
a lami okun ja!
a lami okun ja, nipa eje re
a lami okun ja!
chants [ jaymikee ]
chorus
a lami okun ja, nipa eje re
a lami okun ja!
a lami okun ja, nipa eje re
a lami okun ja!
Random Lyrics
- tyfontaine - enterprise lyrics
- gamingly - guardian angel lyrics
- mulii x snm - motorola lyrics
- blocboy jb - praise the lord lyrics
- il profeta - monopoly lyrics
- blood on the dance floor - total immortal lyrics
- glebbb babki - ходуном по хатам lyrics
- shai linne - private prisons pt. 2 lyrics
- юлдуз усманова (yulduz usmanova) - otayon (otajon) lyrics
- guy davis - got your letter in my pocket lyrics