
jaymikee - talebale lyrics
verse 1
aje bi omode ti iya re ran lo soja
oya ile aye lati ra, lati ta
sugbon ti ile ba bere sin su
ti okunkun ba bole
ti onikaluku ba pale oja mo
ma je kin gbagbe lati kori sile
chorus
jesu o jowo o ma jen kuna
ki ma ba segbe lo se ku fun mi
jesu o jowo o mama jen sina
ki ma ba segbe lo se ku fun mi
nigba talebale toja aye tu
je kin roko re ba rele
je kin roko re ba rele
verse 2
ijoba orun da bi awon wundia mewa
ti won mu fitila won lo pade oko iyawo
eledumare mama jе kin di alaigbon
fun mi ni ogbon bi awon wundia ologbon
kolobo mi ree o rokun pelu ororo re
kin fi duro de o
chorus
jеsu o jowo o ma jen kuna
ki ma ba segbe lo se ku fun mi
jesu o jowo o mama jen sina
ki ma ba segbe lo se ku fun mi
nigba talebale toja aye tu
je kin roko re ba rele
je kin roko re ba rele
bridge
(mu mi dele o o, mu mi dele)
(mu mi dele o o, mu mi dele)
(mu mi dele o o, mu mi dele)
(mu mi dele o o, mu mi dele)
(mu mi dele o o, mu mi dele)
(mu mi dele o o, mu mi dele)
(mu mi dele o o, mu mi dele)
(mu mi dele o o, mu mi dele)
(mu mi dele o o, mu mi dele)
(mu mi dele o o, mu mi dele)
(mu mi dele o o, mu mi dele)
(mu mi dele o o, mu mi dele)
(mu mi dele o o, mu mi dele)
(mu mi dele o o, mu mi dele)
(mu mi dele o o, mu mi dele)
(mu mi dele o o, mu mi dele)
(mu mi dele o o, mu mi dele)
(mu mi dele o o, mu mi dele)
Random Lyrics
- zmiless - loved you lyrics
- skymirals - не влюбиться lyrics
- king bakuyo pro - our secret (fnaf secrets of the mimic song) lyrics
- marked visions - acquire equity lyrics
- ski & wok - si o no lyrics
- saenacra - 1-800-whitetee lyrics
- cartoon & leowi - wait a while lyrics
- izaya tiji - track 4 lyrics
- градусы (gradusy) - пацаны (the boys) lyrics
- eleazar galope - midnight sadness (5th anniversary remix) lyrics