jaymikee - the restorer (olurapada) lyrics
e ba mi ki olurapada
e ba mi ki olurapada
nitori to shey oun pupo fun omo araye
nitori anu re duro lai lai
e bami ki olurapada
e bami ki olurapada
apata aye raye mo ki o o baba mi
alagbara giga giga giga
alagbara to n gba mi lowo ajunilo
kii ba ti la gbara re
ko se un ti la gbara re
olugbala
oludande
olurapada
olugbeja
oluranlowo
ata aiye se e e
ato rise
mo ti fi jeus shey abo oun ni ibi isadi mi
lowo lowo iranlowo baba ti dide iranlowo fun mi
a ti gbemiga ori apata aye raye a ko ni shi mi ni po rara
a ti ramipada
a ti so mi do omo
mo jade ninu idalebi
ah ah ah ah mo gba idalare
ninu jesu oluwa
e ba mi ki olurapada
e ba mi ki olurapada
nitori to shey oun pupo fun omo araye
nitori anu re duro lai lai
e bami ki olurapada
e bami ki olurapada
ara ba ri biti
ari bi rabata
gba ni gba ni ti aye n saya
gba ni gba ni ti orun n bo
olori ogun
asaju ogun
akeyin ogun
akikanju loju ogun
iwo la gba ni lowo ija
baba mi arogun da ade
arogun ma ti di
olugbeja mi oh oh oh
gba ni gba ni
mu ni mu ni
yo ni yo ni
la ni la ni
olusegun
aja segun
o gbe ni ni ija ke ru o bonija lojo ija
baba mi onikan gbe rare nija
ta ni iwo oke ni waju zerubabeli
lojiji odi dan dan ki e di ite mole
mo gboju mi soke ni bi iranlowo mi yio a ti wa
iranlowo mi n be ninu oruko oluwa ah ah ah ah
a ti gbe mi nijaaa
mo ti ju asegun lo
e ba mi ki olurapada
e ba mi ki olurapada
nitori to shey oun pupo fun omo araye
nitori anu re duro lai lai
e ba mi ki olurapada
(chants)…
e ba mi ki olurapada
e ba mi ki olurapada
nitori to shey oun pupo fun omo araye
nitori anu re duro lai lai
e ba mi ki olurapada
e ba mi ki olurapada
Random Lyrics
- bloody hawk, dani gambino & wang - κάθε μέρα (kathe mera) lyrics
- jay bk80m - llkv lyrics
- lil mike (prt) - posse de bola lyrics
- мукка (mukka) - крыльями (wings) lyrics
- indigovox - the dark red sea lyrics
- ghoulies (aus) - self help lyrics
- mitar mirić - doviđenja društvo staro lyrics
- דניאל רובין - zikaron yaldut - זיכרון ילדות - daniel rubin lyrics
- calum scott - yours lyrics
- gabriel (dojang) - drive myself insane lyrics