
jaymikee - to beru lyrics
[intro]
iba, iba, meje, meje
iba, iba, meje
iba, iba, meje, meje
iba, iba, meje
iba o!, oh
iba, iba, meje, meje
toto oba!
iba, iba, meje
toto oba!
iba, iba, meje, meje
iba, iba, meje, meje
[chorus]
toto o toto
toto o to beru
toto o to foya o
oba to daye to da orun
oba tayen warifun o
ooh ooh
toto o to beru o
iba, iba, meje, meje
iba, iba, meje
iba, iba, meje, meje
iba, iba, meje
[verse 1]
okun pupa pin simеji
opari ise igbala wa
omowo jade lenu еja
iru olorun wo leyi o
okun pupa pin simeji
opari ise igbala wa
omowo jade lenu eja
iru olorun wo leyi o
toto o to beru
[chorus]
toto o toto
toto o to beru
toto o to foya o
oba to daye to da orun
oba tayen warifun o
ooh ooh
toto o to beru o
[verse 2]
bino sen yo, aranson
ojon ro ina njo
bino sen yo, aranson
ojon ro ina njo
ohun oluwa nson aara
ohun oluwa f+gi kedari ya
toto o to beru o
bino sen yo, aranson
ojon ro ina njo
bino sen yo, aranson
ojon ro ina njo
ohun oluwa nson aara
ohun oluwa hun f+gi kedari ya
[chorus]
toto o to beru o
toto o toto
toto o to beru
toto o to foya o
oba to daye to da orun
oba tayen warifun o
ooh ooh
toto o to beru o
[verse 3]
ohun oluwa of+gi kedari ya
o joba, o joba, o joba
ohun oluwa, okun fun olanla
o joba, o joba, o joba
ohun oluwa of+gi kedari ya
o joba, o joba, o joba
ohun oluwa, okun fun olanla
o joba, o joba, o joba
Random Lyrics
- cadavar - no more pain lyrics
- skitons - обожаю пятёрку(adore 5opka) lyrics
- xentix - ekseninde lyrics
- a traitor like judas - stones, blood and gold lyrics
- marián varga, pavol hammel & radim hladík - v zelenej pamäti lyrics
- lando bando - why would i get a job? lyrics
- educible - shor lyrics
- bina (srb) - očima moje ljubavi (remix) lyrics
- sir exii - on the road lyrics
- kleenex girl wonder - do you want me? lyrics