azlyrics.biz
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

klement ola-daniels - molólúwa lyrics

Loading...

a
ẹ′rù ò bà mí
e e e e a

àyà ò f’omì
rárá o o

ẹ′rù kò bà mí
ẹ’rù kò bà mí
ẹ’rù kò bà mí
molólúwa o, ye ye

àyà kò f′omì
àyà kò f′omì
àyà kò f’omì
moní bàbá kan, ye ye

ẹ′rù kò bà mí
ẹ’rù kò bà mí
ẹ′rù kò bà mí
moní jésù
alágbára ni

àyà kò f’omì
àyà kò f′omì
àyà kò f’omì
molólúwa o

bàbá awímáyẹhun
asọ’rọ′ má gbàgbé ni, ye

ẹ′rù kò bà mí
ẹ’rù kò bà mí
ẹ′rù kò bà mí
moní jésù l’olúwa, a

àyà kò f′omì
àyà kò f’omì
àyà kò f′omì
ọ’rẹ’ mi ni, ye a

ẹ′rù kò bà mí
ẹ′rù kò bà mí
ẹ’rù kò bà mí
molólúwa o
ọ′rẹ’ mi ni, yes

àyà kò f′omì
àyà kò f’omì
àyà kò f′omì
bàbá mi ni o, a

ọba awímáyẹhun
asọ’rọ’ mátàsé ni, a

a
when i called
òun jẹ mí
when i cried
òun gbọ mi
when in pains
òun rí mi
when in need
òun rí mi

he came to earth to set me free
laid his life to make me king
washed my sins on calvary with his blood
alágbàwí ẹ′dá
agbani+lágbàtón ni
yes

ẹ′rù ò bà mí
àyà kò f’omì
molólúwa o, yes

àyà kò f′omì
ẹ’rù ò bà mí
moní bàbá kan
alágbára ni
ọba awímáyẹhun
asọ′rọ’ má gbagbé ni, ye

ẹ′rù kò bà mí
ẹ’rù kò bà mí
ẹ’rù kò bà mí
molólúwa o, ye ye

àyà kò f′omì
àyà kò f′omì
àyà kò f’omì
ọ′rẹ’ mi ni, ye

ẹ′rù kò bà mí
ẹ’rù kò bà mí
ẹ′rù kò bà mí
molólúwa o
ọ’rẹ’ mi, yes a a a

àyà kò f′omì
àyà kò f′omì
àyà kò f’omì
moní bàbá kan

ọba awímáyẹhun
asọ′rọ’ mátàsé ni



Random Lyrics

HOT LYRICS

Loading...