
majur - oxalá lyrics
ajagunà gbà àwọ̀, ajagunà
ajagunà gbà àwọ̀, ajagunà
elémoṣọ̀ bàbá ológun
ajagunà gbà àwọ̀
ajagunà gbà àwọ̀, ajagunà
ajagunà gbà àwọ̀, ajagunà
elémoṣọ̀ bàbá ológun
ajagunà gbà àwọ̀
ajagunà gbà àwọ̀, ajagunà
ajagunà gbà àwọ̀, ajagunà
elémoṣọ̀ bàbá ológun
ajagunà gbà àwọ̀
ajagunà gbà àwọ̀, ajagunà
ajagunà gbà àwọ̀, ajagunà
elémoṣọ̀ bàbá ológun
ajagunà gbà àwọ̀
ò fúrùrú lóòréré o
àìláà bàbá kényènyè ní ejìgbò
ilé ìfọ̀n mo ti wá, bàbá
ejìgbò rere, mo júbà ó
olúwa, ẹ má wòró, ẹ má wòró alẹ́ ṣe
ò fúrùrú lóòréré o
àìláà bàbá kényènyè ní ejìgbò
ilé ìfọ̀n mo ti wá, bàbá
ejìgbò rere, mo júbà ó
olúwa, ẹ má wòró, ẹ má wòró alẹ́ ṣe
ò fúrùrú lóòréré o
àìláà bàbá kényènyè ní ejìgbò
ilé ìfọ̀n mo ti wá, bàbá
ejìgbò rere, mo júbà ó
olúwa, ẹ má wòró, ẹ má wòró alẹ́ ṣe
ò fúrùrú lóòréré o
àìláà bàbá kényènyè ní ejìgbò
ilé ìfọ̀n mo ti wá, bàbá
ejìgbò rere, mo júbà ó
olúwa, ẹ má wòró, ẹ má wòró alẹ́ ṣe
àṣẹ, bàbá
ọlọrun orílẹ̀
ọṣàlá bèsí fún ọ
ẹ̀bẹ̀ bàbá
oníṣà wúrè, àwọn l’àṣẹ
onisá wure oberi omã
oníṣà wúrè
àwọn l’àṣẹ, bàbá
onisá wure oberi omã
oníṣà wúrè, àwọn l’àṣẹ
onisá wure oberi omã
oníṣà wúrè
àwọn l’àṣẹ, bàbá
onisá wure oberi omã
oníṣà wúrè, àwọn l’àṣẹ
onisá wure oberi omã
oníṣà wúrè
àwọn l’àṣẹ, bàbá
onisá wure oberi omã
o navio negreiro não foi
um encontro marcado
a gente resiste
por não ser cultura, no nosso país
aquilo que deveria ter sido
então, eu refaço esse caminho novamente
e, através dеsse novo navio
encontra+se, na bahia
e a gentе, enfim, pode viver
a cultura africana no país chamado
brasil
Random Lyrics
- x1n3 (x1n3off) - prxjek-fightme! (remix) lyrics
- פאר טסי - ze lo meshane - זה לא משנה - peer tasi lyrics
- hamell on trial - drunk dial me lyrics
- ofuh real - inhale(good night) lyrics
- nick nemesi - cielo lyrics
- vishal mishra - alvida lyrics
- gabriel delfito - fica pra sempre lyrics
- agatka iskra - tik tok (2022 remix) lyrics
- abigail stauffer - love song of earth and sky lyrics
- golden cats - inside your mind lyrics