azlyrics.biz
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

mo'believe - bi oba lyrics

Loading...

[intro: mo’believe]

mobọ́, mo’believe

olumba lo shey beat

[chorus: mo’believe]

eré dé, ọmọ a rí jó ṣe bí ọba

ẹ̀fẹ̀ dé, ọmọ a rí jó ṣe bí ìjòyè

ìlẹ̀kẹ̀ ló ma jẹ ìyá l’álẹ́ ọ̀ní

òní gángàn bá mi lùlù sí ìbèbè dí

torí

eré dé, ọmọ a rí jó ṣe bí ọba

ẹ̀fẹ̀ dé, ọmọ a rí jó ṣe bí ìjòyè

ẹ gbé rin sí orin mi

[verse 1: mo’believe]

a mú ludùn ẹ má pè wá l’álágbe (2x)

à wá ti dé pẹ̀lú àtúndá eré (2x)

[bridge: mo’believe]

eré dé, ọmọ a rí jó ṣe bí ọba

ẹ̀fẹ̀ dé, ọmọ a rí jó ṣe bí ìjòyè

[verse 2: mo’believe]

àgbàlagbà wá n sọ̀ pá nù

ọmọdé wá n sọ̀ ìtìjú nù

t’abá ti bọ́ sí ágbo eré

egungun gbígbẹ ṣá ma n dìde

[chorus: mo’believe]

eré dé, ọmọ a rí jó ṣe bí ọba

ẹ̀fẹ̀ dé, ọmọ a rí jó ṣe bí ìjòyè

ìlẹ̀kẹ̀ ló ma jẹ ìyá l’álẹ́ ọ̀ní

òní gángàn bá mi lùlù sí ìbèbè dí

torí

[bridge: mo’believe]

eré dé, ọmọ a rí jó ṣe bí ọba

ẹ̀fẹ̀ dé, ọmọ a rí jó ṣe bí ìjòyè

ẹ gbé rin sí orin mi

[verse 3: mo’believe]

a mú ludùn ẹ má pè wá l’álágbe

a mú ludùn ẹ má pè wá l’álágbe

òhun orí rán wa ṣé òun la wá ṣe

ẹ̀rí à tí pà gọ̀, èró ti jáde

orin ló sọ wá di ẹni ọba ń kí

orin ló sọ wá di ẹni ìjòyè ń kì

orin ló sọ wá di ẹni ayé ń fẹ́

a mú ludùn ẹ má pè wá l’álágbe

a mú ludùn ẹ má pè wá l’álágbe

a mú ludùn ẹ má pè wá l’óní yẹ̀yẹ

a mú ludùn ẹ má pè wá l’álágbe

orin ló sọ wá di ẹni ayé ń fẹ́

[chorus: mo’believe]

eré dé, ọmọ a rí jó ṣe bí ọba

ẹ̀fẹ̀ dé, ọmọ a rí jó ṣe bí ìjòyè

ìlẹ̀kẹ̀ ló ma jẹ ìyá l’álẹ́ ọ̀ní

òní gángàn bá mi lùlù sí ìbèbè dí

torí

[bridge: mo’believe]

eré dé, ọmọ a rí jó ṣe bí ọba

ẹ̀fẹ̀ dé, ọmọ a rí jó ṣe bí ìjòyè

ẹ gbé rin sí orin mi



Random Lyrics

HOT LYRICS

Loading...