azlyrics.biz
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

mosimiloluwa - modupe lyrics

Loading...

modupe pe mo ri odun tuntun

modupe pe mo ri odun tuntun

emi mi to beere re, ni yi yo la’ja

modupe o, pe mo ri odun tuntun ( iwo nko)

modupe pe mo ri odun tuntun……

ose olu’orun, ose olu’orun o, bo gun ti po to le’shi, o’jo gbemi mi
ose o, olu’orun ( iwo lo jo gbemi wa)

ose olu’ orun, ose olu’orun o, bogun ti poto le’shi, ojo gbee’mi mi, ose o olu’orun

chorus

iji ja le’shi, ile npoyi o

sugbon sa ko do’mi nu agbon nu

ota fe kin nrin hoho woja, won fe kin ti de’ni igbagbe o, sugbon sa o, mo’ranu gba

chorus

lodun eyi ma ri ta’je se

lodun eyi ma rona gbe gba

mi oni ta wo na, me ni too’ro je

ibukun oluwa o, ama bami gbe.( ni wole ati jade)

chorus

ire owo re, ire owo re, ire owo re ,( olopo ire) eledumare ni mo hun too’ro( je kin nri ire odun tuntun toka si)
baba je kin ni ani’to, jekin ni ani seku,( je ki ibukun wo le mi)

je kin ma win orileede mama je kin ntoo’ro, je kaye kimi ku ori re, lati january ri o titi wo december o

modupe pe mo ri odun tuntun…

kaabo nigeria si odun itura( oku ogun ajabo orileede mi)

mo sotele loruko oluwa

konga re yo kan omi

owo a paro owo itura ade

owon ado’po o, lorileede ee wa

ire owo re, ( olopo ire)ire owo re, ire owo re, eledumare ni mo hun too’ro



Random Lyrics

HOT LYRICS

Loading...