oladips, bhadboi oml, illiterate - chaos lyrics
intro
óbèlè wèlùwè
illiterate
(maximus, maximus), óbèlè wè’
ọmọ égbá dè (the disciples music)
óbèlè wè, é shèè’mí
óbèlè wè, wè+wè
verse
ọlabode l’òrukó mi, òriki mi l’adisa
wọn mó mi n’ilé álawó dùdù n’dèdè africa
ambition mi tobi gan, ambition mi rópótó
kin ma b’áwọn èyinbò jeun ninu ábọ wọn yọkótó
b’obá s’eyinbo si mi, èmi na á dè soh yor’ba
kinwá j’óba l’èwọn l’óri, t’éni t’ọma soh d’ọgá
b’èyankan bà bèh si mi, k’oló bàmi ju sinu tüübù
ẹni t’óba bà yásò pà, iru èyàn bè, kó kin sun mù
verse
illiterate ni min l’òòtó, iwè timò ká, ò por
sugbón mò mó maths, mò mó addition, mò mó áròpó
ẹlè r’òmi l’òjùmi, t’òri+emi ò bàwón r’árokàn
ti bámi ò ba lowò máalu, má yá bàwón pá aguntàn
ẹmi yátó s’àwọn kàn, tóh ma’n fake perfection
wọn bà mà jin si kòtò, kàlò take direction
è s’èni yò mò tàn, è s’èni mistake ò lè bà
nkàn t’ọmówè bà gbá, illiterate ò lè gba
chorus
moti shèè tan, é gbè mi
òyá, é gbè mi (òyá, é gbè mi)
ẹ ma fi’na gbè mi
òyá, é gbè mi (òyá, é gbè mi)
ah, i don’t lie, i’ll jéébi
áráyin n’ekiló fun, áráyin n’ekiló fun
áráyin n’ekiló fun
ọmu yágo o kin s’ọre ẹnikan, ọmọyin n’ekiló fun
angel gabriel in heaven, angel gabriel in heaven
hook
moti shèè tan, é gbè mi
òyá, é gbè mi (òyá, é gbè mi)
ẹ ma fi’na gbè mi
òyá, é gbè mi (òyá, é gbè mi)
verse
ẹmi l’ọtolorin, number one, è dè si counterfeit
ishèè élèyi yátò, ishèè èlèyí l’on pè ni masterpiece
b’imba fẹ to l’oru, èmi nikàn ni mó man dá p+ss
so, málo photo+bomb selfie mi, ah tinbá shà pics
shout+out s’áwọn t’èmi l’égba, mò mó pè oriyin mà swell
at’awọn t’ómá gb’orin mi, t’òma bèèrè sini ma twerk
awọn ọmọmi kafila, awọn ọmọmi baliki
awọn ọmọ t’ojèpe, gbogbo abẹ wọn ni mo s’aami si
verse
gbẹgede gbinà, egedè fẹ yèwò (yèwò)
ẹjenfisiyin l’ẹgbéwò wò
wọnjo pè wa si show l’ójósi, sugbón é l’ána, èmi ni sisi yin dè fẹwo (fẹwo)
l’ẹwa d’eni tó k’eshèè bo (‘shèè bo)
tioba s’ẹba, lojẹ semo
ko sháá ti gba kadara lo shèè koko
mà pada si ésé aaro, má pada si’zero
verse
ah, wọn ni pè mo high b’ẹni pè moti fa cannabis
èmi tun ni rapper ton kó lyrics pélu arabic
“game changer” l’ónpé mi, leader of the new school
awọn agba gan timo reason t’awọn o dè fini sùn, ah
chorus
moti shèè tan, é gbè mi
òyá, é gbè mi (òyá, é gbè mi)
ẹ ma fi’na gbè mi
òyá, é gbè mi (òyá, é gbè mi)
ah, i don’t lie, i’ll jéébi
áráyin n’ekiló fun, áráyin n’ekiló fun
áráyin n’ekiló fun
ọmu yágo o kin s’ọre ẹnikan, ọmọyin n’ekiló fun
angel gabriel in heaven, angel gabriel in heaven
hook
moti shèè tan, é gbè mi
òyá, é gbè mi (òyá, é gbè mi)
ẹ ma fi’na gbè mi
òyá, é gbè mi (òyá, é gbè mi)
outro
óbèlè wèlùwè, óbèlè wèè
Random Lyrics
- yute - pearl gate lyrics
- the everly brothers - walk right back (polskie tlumaczenie) lyrics
- los pleneros de la cresta - café con ron (part. bad bunny) lyrics
- sunset sweatshop - move it lyrics
- chapelll - bitch made lyrics
- vero (swe) - spin lyrics
- 1crusafix - myself lyrics
- gv - sunshine (avantis remix) lyrics
- энэстэ (eneste) - бегать за тобой (run after you) lyrics
- chriles - radioconnectedvcr lyrics