azlyrics.biz
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

oluwamillar - muri lyrics

Loading...

[hook: jamz fr]
oh lord have mercy on the boy
no, we kú no get no choice
na the hustle turn the boy into a sinner
ahn ahn ahn
ọmọ wọn ǹ ríwa

[verse 1: oluwamillar]
àbúròs hitting up his phone
(bùkátà pọ̀ gan)
kò rorò, ìyà ló pọ̀ t’ọ́mọ fi bone
(ọlọ́un)
ó tó b’ọdún mẹ́wàá daddy muri ti ní stroke (guy)
ma passed four years ago, ayé yìí choke (ọmọ ó ga ò)
sister wọn ti lọ america ǹnkan bi five years
day wey she comot, e been fight tears
pé ‘ṣẹ́ ti ṣẹ́, but ikú ṣ’òjóró, she died there
ẹ̀dá ò l’idea à ń p’ọlọ́run l’ẹ́
jọ́, the guy tear
dropped out uni to fend for the young ones (bẹ́ẹ̀ni)
final year, second semester, maa gbọ́ ǹnkan
e long gan, ayé tó wicked ju young jonn
àárù ni ò gbé ni, àbí kò ru pọn+ọn+pọ́n
kò s’árá, kò s’helper, kò s’ẹ́bí, kò s’álábàárò
bro, sapa no send man, ko tẹ́
‘tí, ko dá matter rò
where we wan waka go?
“aà lè sálọ for this life, baba wo”
l’alayé fọ, strive
kó máa tò gb’ẹ́yìn, no cannavaro
ahn ahn ahn ahn
[hook: jamz fr]
oh lord have mercy on the boy
no, we ku no get no choice
na the hustle turn the boy into a sinner
now we dey bomb like shekau
know my brothers gottu chow
before men, na john cena, wọn ǹ ríwa
ooh lord have mercy on the boy
no, we kú no get no choice
na the hustle turn boys into sinners
and now they bomb like shekau
my brothers gottu chow
‘fore before, na john cena, wọn ǹ ríwa

[verse 2: oluwamillar]
muri hustle like who collect date
(bí ẹní gb’ọjọ́)
wọ́n ní muri wá maga ko kú gb’ọpẹ́ straight
o dẹ̀
lelè j’ọ́sẹ 2 for 10 bay
ó kọ̀
jálẹ̀, ó l’ótì, ó tún ‘ṣọ ṣẹ́ ṣe
l’ọ́
jọ́
‘jọ́ kan ní joint kan t’ótí ń ṣe bar boy
màmá tó ni bar sáré jáde bí ẹní tascoin
ẹ̀ẹ̀fun ab’èèdì, mama, ẹ wá kíni problem?
wọ́n ti jí mi l’ówó àjọ ń yàrá, ǹnkan bi 1m
muri wá ń bí, ìwọ ṣá lo gbá yàrá
eré ab’àwàdà ‘rá ‘dúgbò dàá l’ábàrá
tifọ́
jú tìfọ́nú ni, beating l’ọba kádàrá
àṣé kwame ló gb’ówó, ìyẹn ọmọ mama ghana
kwame fi 1 million ta virtual (ajá ń sáré)
tán ti na muri pa casual
ojú ga, ẹsẹ̀
lọ́, ẹ̀kẹ́ times four
wọ́n ní gba f’ọlọ́un, muri gba lappie, ó gba turn
ahn ahn ahn ahn
[hook: jamz fr]
oh lord have mercy on the boy
no, we ku no get no choice
na the hustle turn the boy into a sinner
now e dey bomb like shekau
know my brothers gottu chow
before men, na john cena, wọn riwa
oh lord have mercy on the boy
no, we kú no get no choice
na the hustle turn boys into sinners
and now they bomb like shekau
‘fore before, na john cena, wọn ǹ ríwa

[outro: oluwamillar]
ọmọ tell me what you gon do
life it ain’t soft boo
chief, e be kung fu uhh
omo tell what you gon do
when e be like say all your dreams no wan come true uh
ahn ahn ahn ahn ahn
ahn ahn ahn ahn ahn
i know sh+t no fair
ah, nah, nah, nah, nah
ah, nah, nah, nah, nah
i know sh+t’s not fair



Random Lyrics

HOT LYRICS

Loading...