
oluwatunmise awoyemi - pa mi mo lyrics
Loading...
chorus: kiki eni o pamo
loyo ninu ewu gbogbo oh oh
s’abomi, pamimo o
ki nmase s’ode ja.(3ce)
”oluwad! lowo re ni no fi emi mi le.”
verse 1: jesu mi
alaabo gbogbo oh oh
s’abomi, pamimo o
ki nmase s’ode ja.(2ce)
(back to chrs)
verse 2: abo emi at’ara tire ni
pamimo o, ki nmase s’ode ja
atilo, atibo, oluwa tire ni
pamimo o, ki nmase s’ode ja
jesu mi
alaabo gbogbo oh oh
s’abomi, pamimo o
ki nmase s’ode ja.(2ce)
(back to chrs)(2ce)
”dawa si oluwa
verse 3: ohun gbogbo ni mo file o lowo, oluwa
pamimo o, ki nmase s’ode ja
olorun aabo ile goseni, oluwa
pamimo o, ki nmase s’ode ja
(back to chrs)(2ce)
”dami si tiletile”
Random Lyrics
- astawav & garp - kosename lyrics
- natureplayer - everyear lyrics
- linkolin - ворканье (the cooing) lyrics
- kolme - remind me... lyrics
- shadzurpp - eu tenho um sonho lyrics
- leilahimikat - припадки ii (seizures) lyrics
- ¥$, kanye west & ty dolla $ign - 530 [updated version] lyrics
- no chance! (band) - time warnings lyrics
- emerson b. ocampo - flipping the autocracy lyrics
- megamat - just look my way (from "helluva boss") (english version) lyrics