oriyomi kehinde - óoré lyrics
interlude
mashaallah
eyi timo ranti bere ninu oore, eyi ti nranti bere ninu oore o
maf′ikankan, dunmi nibe oba nla
eyi timo ranti bere ninu oore, eyi ti nranti bere ninu oore o
maf’ikankan, dunmi nibe oba nla
tor′odi o loun tole fi toro, sungbon o lokan tole fi beere
o sha nd’odi loun lori oore, kod’igba tinba so soke kaye o gbo o
koto dami loun oba nla ilahi
eyi timo ranti bere ninu oore, eyi ti nranti bere ninu oore o
maf′ikankan, dunmi nibe oba nla
yah robbi koma s′oba meji ti momo, l’oba tiwon npe l′olohun
toba j’ese ti emi tinse, t′iyen fema dina ati gb’ore
emi nf′akoko yi toro, aforijin lodo re o allah
eyi timo ranti bere ninu oore, eyi ti nranti bere ninu oore o
maf’ikankan, dunmi nibe oba nla
bee, mo l’awon nkan l′afojusun repete, nkan to wumi lokan pe kin ni
o wumi kin nile pupo timo ko o, pelu ile ise topo repete
kin mari bukata gbo l′agbo dale o, kemi ma f’ewu ogbo agba t′ore
eyi timo ranti bere ninu oore, eyi ti nranti bere ninu oore o
maf’ikankan, dunmi nibe oba nla
mo kepe e olohun mi, mo kepe e olohun mi,
olohun jowo wa rami kale, majen r′isoro
mo kepe e olohun mi, olohun jowo wa rami kale, majen r’isoro, naam
ogun k′eda le koma leba, k’eda fa koma to’rawon
iyen o wumi wa rami kale, maje nri′soro, olohun oba
mo kepe e olohun mi, olohun jowo wa rami kale, majen r′isoro
allah, je k’enu mi t′oro ninu ebi wa,
ma fami seyin ninu egbe kin tayo
agbega lemi nfe, wa famisoke, oba alaranse, olohun oba
mo kepe e olohun mi, olohun jowo wa rami kale, majen r’isoro
emi o sope owo o je nkan, miio de gbe′yi fun’le aye j′orun lo
sungbon owo l’ale fise pupo n’nu ise ore toni kama se, mofe ma t′ore
mo kepe e olohun mi, olohun jowo wa rami kale, majen r′isoro
mashaallah, oluwa mi, oriyomi lemi nje, moti f’oro mi gbogbo, fi l′oluwa lowo
gbogbo ireti oore, je o tomi lowo ooo oti f’oro mi gbogbo, fi l′oluwa lowo ha
mote f’oro mi gbogbo, fi l′oluwa lowo, moti f’oro mi gbogbo, fi l’oluwa lowo
gbogbo ireti oore, e o tomi lowo o, moti f′oro mi gbogbo, fi l′oluwa lowo
a leni ma deyin ma deyin ota ile ton o fe ka r’ibi mi mo
kos′iru áàlò t’ale se, kotun kin tewon lorun, bi k′ama se wa laye mo, lori loju ota wa
mio ni ku f’ota yo lailai, ma gbe′le aye seun rere o
moti f’oro ota gbogbo, fi l’oluwa lowo won gbe
moti f′oro mi gbogbo, fi l′oluwa lowo, moti f’oro mi gbogbo, fi l′oluwa lowo
gbogbo ireti oore, e o tomi lowo o, moti f’oro mi gbogbo, fi l′oluwa lowo
seri ibanuje ota nipe, won nrimi pe mo cute
mio toro óbè tun gb’abo, losile awon eyan won
kobe kiwon le so pe ebi pami de ile odo won
atije atimu mi, mafi l′otami lowo, awon oro mi gbogbo, lowo oluwa lo ngbe
allahumma ina, aj+aluka fii, nuh+rihim
wa naudzu bika min, shururihim
allahuma akfinihim, bima shi+ita, allahuma anta a+duhdi
wa anta nasriy, bika ajulu wa bika, asuulu
wa bika uqotil, hasbuna laha, wa ni+imal wakeel
moti f’oro mi gbogbo, fi l’oluwa lowo, moti f′oro mi gbogbo, fi l′oluwa lowo
gbogbo ireti oore, e o tomi lowo o, moti f’oro mi gbogbo, fi l′oluwa lowo
ok, eti e gbo, wona enemy mi da? won ti wo’gbo, won ti ra m′aye
awon abinu eni da now? won ti wo’gbo, won ti ra m′aye
awon amoni seni da? won ti wogbo, won ti ramaye
awon ota ologo da? won ti wo’gbo, won ti ra m’aye
awon ápání máyo′dà? won ti wo′gbo, won ti ra m’aye
tojepe loru na ma nfase ja? won ti wo′gbo, won ti ra m’aye
ise ti ati nsebo lati ipile wa, kole da ti ati nbabo lati ibere wa o
eyi toku tota ndina ma salai shio, sebaje mafe gbayi nidi ibaje o
da′na súnwon konma file r’aye t′awa mo, nitoripe
b’olohun se nsore e fun eru (ota ngbogun ati tuka, yes
ani b’olohun se nsore e fun eru, ota ngbogun ati tuka
awa gbeke lolohun, ota ngbogun ati tuka
b′ase gbeke lolohun, ota ngbogun ati tuka
eyin e ma wo′ran, e file o, ise lo gba o, fe s’eru ku niyen
oya, so p′otami yeye aye e, yeyee, yeye aye e
bimose nrije rimu kole ye e, ko lee, kole ye
bimose nri t’owo se kole ye e ko lee, kole ye
bimose ntoju ayemi, kole ye ko lee, kole ye
gbogbo lilo bibo mi kole ye e, ko lee, kole ye
b′awon aye se nfemi kole ye e, ko lee, kole ye
amóni séni ota ile, ko lee, kole ye
olohun
mafi’koro simo o, mafi′koro simo, mafi’koro simo, mafi’koro simo
adua mi ti ngba, dakun ba nsalekun, toba semi bimose fe o, ope mi onitan
mafi′koro simo o, mafi′koro simo, adua mi ti ngba, dakun ba nsalekun, toba semi bimose fe o, ope mi onitan
opo oore eda laye o,lonyi s’ibanuje
olohun ilahi, ma mase t′awa be
towo batie wa wa, t’alafia o basi
kini igbadun owo, se ka l′ore èdé ni
ore ti o po dale oo, ore ti o po dale, olohun lemi fe
mafi’koro simo o, mafi′koro simo, adua mi ti ngba, dakun ba nsalekun, toba semi bimose fe o, ope mi onitan
won ni b’eye ègà kole o, yio f’enu re tu tan
sebi funra ólókùnrùn, lo nfenu re pe iku, oore ti mo nfe o, pe kose ilahi
toba ma dinira, dakun ba ns′atunse, toba semi bimo se fe o, ope mi o nitan
mafi′koro simo o, mafi’koro simo, adua mi ti ngba, dakun ba nsalekun, toba semi bimose fe o, ope mi onitan
mashaallah, moti nj′eni aponle o, maje npada wa te
aye npemi s’ariya, t′owo pelu ebun nla, won nsemi l’anu, won a tun s′adua funmi
mo l’olohun ma lase, loba sina anu, laba tun se’dera o, k′opeyemi le tele
mafi′koro simo o, mafi’koro simo, adua mi ti ngba, dakun ba nsalekun, toba semi bimose fe o, ope mi onitan
oriyomi, mo dupe f′awon fans, ton nf’owo ra data
adupe f′awon fans, ton nf’owo subscribe
adupe f′awon fans, ton, nfojojumo lo skit
ope to seyin fans, te nf’owo ra cd, bee
pelawon fans kan, ton npewa s’ode ere ton nawo, akanni, adua mi nipe o, k′olohun tunma se′bukun
oba o ni dawo ola duro
gbogbo be senri temi ro o, lolohun a ma ro’jo ike
oba oni dawo ola duro
gbagbo bese nfimi s′okan l’olohun a ma se′dunnu
oba oni dawo ola duro
hajji ibraheem dende, alase ibd ajao
oba oni dawo ola duro
sheu ganiyu akewushola olohun ni idahun s’adua
oba oni dawo ola duro
hajji razak arolat mi, ágbã owo tonpe l′àgbà awo
oba oni dawo ola duro
akeweje iseyin, baba adini of nigeria, oba oni dawo ola duro
alhaji lukman mi o, omo sh+ttu zangallo zanga
oba oni dawo ola duro
alhaji ridwaanullahi, olamilekan dansokoto
oba oni dawo ola duro
akanmu agba omo bakare o, hajji rashidi agunwa
oba oni dawo ola duro
hajji saheed omo olayode o, akan’o oko ejire, oba oni dawo ola duro
omo agbaje shereefdeen mi, ola salam ni okan ni, oba oni dawo ola duro
babatundé ibon, abdul majeed l’olufimo, oba oni dawo ola duro
mio je gbagbe awon manager mi, tajo nse tofi ndun to ndan, oba oni dawo ola duro
ayesoro innocent ahmed, baba aliyah oko nafisat
oba oni dawo ola duro
adisa ade emir mi, ayomide ismaheel, oba oni dawo ola duro
owolabi lukman mi, baba fausat anisere, oba oni dawo ola duro
irawo toyeeb olamilekan, steady boy akorin ni
oba oni dawo ola duro
Random Lyrics
- martyk - just fine lyrics
- димдэкт (dimdekt) - доярка 2 (doyarka 2) lyrics
- blue in heaven - all you fear lyrics
- cedric brazle - rush lyrics
- pərviz qasımov - mənim azərbaycanım lyrics
- dissidia - scheine jeden tag lyrics
- squallor - no se bibe così lyrics
- dragonland - a light in the dark lyrics
- setnix - выбыл [dropped out] lyrics
- leyla mccalla - mesi bondye lyrics