paul i.k. dairo - mo sori ire lyrics
intro
the remix, believe it or not (the remix, love)
the remix, believe it or not (yeah), believe it or not, believe it or not (yeah)
this is how it should be done (uh, uh)
’cause this style is identical tonight (what, what?) how can i make you dance? (c’mon)
pd, that’s what you came here for, right? (that’s what you came here for) (alright, alright)
verse
ẹlẹda mi, mọ di ẹ mú
mọ di ẹ mú
ẹlẹda mi, mo di ẹ mú, mi ò gbọdọ jabọ
ẹlẹda mi, mo di ẹ mú, baba, mọ di ẹ mú
ẹlẹda mi, mo di ẹ mú, mi ò gbọdọ jabọ
mo wà dùpẹ ore àná, baba, mo dùpẹ o
mo wà dùpẹ ore eni, baba, mo dùpẹ o
mo tún dùpẹ ore ọlá, baba, mo dùpẹ o
baba, mo dùpẹ o, baba, mo dùpẹ o
baba, mo dùpẹ o, baba, mo dùpẹ
chorus
bí mo bá ji l’òwúrọ kùtùkùtù, ma d’orí mí mú
mo ṣorí rè o, ẹlẹda mi, mo dùpẹ o
bí mo bá ji l’òwúrọ kùtùkùtù, ma d’orí mí mú
mo ṣorí rè o, ẹlẹda mi, mo dùpẹ o (baba)
mo ṣorí rè o, ẹlẹda mi, mo dùpẹ o (baba)
mo ṣorí rè o, ẹlẹda mi, mo dùpẹ o
verse
ọlọ́run àgbáyé, ọlọ́run àgbáyé
ọlọ́run àgbáyé, ọlọ́run àgbáyé
iwọ nìkan ni ìgbẹ́kẹ̀lé mí, ìwọ nìkan ni ìgbẹ́kẹ̀lé mí
baba, baba, baba, baba, baba, baba, baba, baba, olúwa
b’ọmọdé ba dùpẹ ore àná, ari omiran gbá
kò ṣeni tó lè ṣe bí kí n ṣe iwọ o
chorus
bí mo bá ji l’òwúrọ kùtùkùtù, ma d’orí mí mú
mo ṣorí rè o, ẹlẹda mi, mo dùpẹ o
bí mo bá ji l’òwúrọ kùtùkùtù, ma d’orí mí mú, ah
mo ṣorí rè o, ẹlẹda mi, mo dùpẹ o (baba)
mo ṣorí rè o, ẹlẹda mi, mo dùpẹ o (baba)
mo ṣorí rè o, ẹlẹda mi, mo dùpẹ o
bridge
hm, o ya, hm, o ya, hm
ẹ jẹ ka dùpẹ lọwọ ọlọrun, ei
ẹ jẹ ka dùpẹ lọwọ ọlọrun, mo tí ṣorí rè
ẹ jẹ ka dùpẹ lọwọ ọlọrun, ei+ei+ei
ẹ jẹ ka dùpẹ lọwọ ọlọrun
ah, easy, woske, ah+ah, easy, oyo, ode+skeskeske
verse
ẹlẹda mi, mọ di ẹ mú
mọ di ẹ mú
ẹlẹda mi, mo di ẹ mú, baba, mi ò gbọdọ jabọ
ẹlẹda mi, mo di ẹ mú, mọ di ẹ mú
ẹlẹda mi, mo di ẹ mú, mi ò gbọdọ jabọ
ọlọ́run àgbáyé, ọlọ́run àgbáyé
ọlọ́run àgbáyé, mi ò gbọdọ jabọ
kò ṣeni tó lè ṣe bí kí n ṣe iwọ o, kò ṣeni tó lè ṣe bí kí n ṣe iwọ o
atẹrẹrẹ kárí ayé
chorus
bí mo bá ji l’òwúrọ kùtùkùtù, ma d’orí mí mú, ah
mo ṣorí rè o, ẹlẹda mi, mo dùpẹ o
bí mo bá ji l’òwúrọ kùtùkùtù, ma d’orí mí mú
mo ṣorí rè o, ẹlẹda mi, mo dùpẹ o
baba, mo dùpẹ o, baba, mo dùpẹ o (mo ṣorí rè o, ẹlẹda mi, mo dùpẹ o)
baba, mo dùpẹ o, baba, mo dùpẹ (mo ṣorí rè o, ẹlẹda mi, mo dùpẹ o)
mo tí ṣorí rè, baba, mo tí ṣori rè, baba o (mo ṣorí rè o, ẹlẹda mi, mo dùpẹ o)
mo tí ṣorí rè, baba, mo tí ṣori rè, baba o (mo ṣorí rè o, ẹlẹda mi, mo dùpẹ o)
chorus
atẹrẹrẹ kárí ayé (mo ṣorí rè o, ẹlẹda mi, mo dùpẹ o)
atẹrẹrẹ kárí ayé o (mo ṣorí rè o, ẹlẹda mi, mo dùpẹ o)
(mo ṣorí rè o, ẹlẹda mi, mo dùpẹ o) bí mo bá ji l’òwúrọ kùtùkùtù…
baba, baba (mo ṣorí rè o, ẹlẹda mi, mo dùpẹ o)
baba, o ṣe, baba, o ṣe (mo ṣorí rè o, ẹlẹda mi, mo dùpẹ o)
mo dùpẹ o, mo dùpẹ o (mo ṣorí rè o, ẹlẹda mi, mo dùpẹ o)
mo dùpẹ lọwọ rẹ, baba (mo ṣorí rè o, ẹlẹda mi, mo dùpẹ o)
mo dùpẹ, mo dùpẹ, mo dùpẹ (mo ṣorí rè o, ẹlẹda mi, mo dùpẹ o)
(mo ṣorí rè o, ẹlẹda…)
Random Lyrics
- galoruff - dónde estás girl lyrics
- los acosta - en algún lugar (versión 30 pegaditas) lyrics
- уже слишком (uzhe slishkom) - real man lyrics
- joey marshall, doğu tan & smoky - gri lyrics
- machine girl - psychic attack lyrics
- kim deal - a good time pushed lyrics
- tyler halverson - nobody’s everything lyrics
- kaii raw - чувствую (i feel) lyrics
- aki - dom vill se dig dö lyrics
- simona (deu) - kriegerin lyrics