
pee'n'oh - àbà bàbá ( àbà father) lyrics
Loading...
a ń pè ọ′
nínú ìdákẹ’jẹ′ ọkàn wa
àbà baba
ẹni tó mọ wá, t’ó mọ’ wá
t′ó nífẹ′ wá,t’ó ń bọ′ wá mọ’ra
èyí ni orin ìtẹríba, orin ìgbẹ′kẹ’lé wá—
àbà baba, ògo ni fún baba”
ọlọ′run baba mi
alágbàwí níí ṣe
ọlọ’run baba mi
ẹni ńlá, tó ńṣe hùńlá
ọlọ’run baba mi
alágbàra gíga ni
alágbàra ni ọlọ′run baba mi
ó dé orí mi ládé
ọlọ′run baba mi
alágbàwí níí ṣe
alágbàwí ni ọlọ’run baba mi
ó dá mi láre
ta ra ra ra
ta ra ra ra
ta ra ra ra (ọlọ′run ni baba mi)
mo ti múra (ó ti dé mi ládé)
ọlọ’run baba mi
alágbàwí níí ṣe
ọlọ′run baba mi
ẹni únlá, tó ń ṣe hùńlá
ọlọ’run baba mi
alọ′run níí ṣe
alọ’run ni ọlọ’run baba mi
ó dé orí mi ládé
ta ra ra ra
ta ra ra ra
ta ra ra ra (ọlọ′run baba mi)
mo ti múra (ó ti dé mi ládé)
Random Lyrics
- vasif məhərrəmli - havalanmış bir adam lyrics
- shea salisbury - are you there, do you care lyrics
- demian deu - la sombra lyrics
- brauxelion - nasty-bot lyrics
- lauana prado - filtro dos sonhos lyrics
- illest morena - eastside luv lyrics
- fluancÿ - mercure lyrics
- oni - erase lyrics
- басота (basota) - звезда давида (zvezda davida) lyrics
- indomitable human spirit - love is strange lyrics