qdot alagbe - otilo lyrics
(2t uponthebeat)
qdot l’oruko mi
omo’mo moriamo
omo o le buru titi, k’afi f’ekun pa je
e bami gbe oluwa tobi, lekan ti yi pada
ko mu’gbo mo (loud lon fa)
ko fa cigar (shisha lon fa)
ko gba jedi (molly lon gba)
t’oba ti gb’oja, ma na soldier
ko mu’gbo mo oh (loud lon fa)
ko fa cigar (shisha lon fa)
ko gba jedi (molly lon gba)
t’oba ti gb’oja, ma na soldier
(otilo)
owo t’oba wo “wan+wan” (otilo)
oole t’oba wo’nu eko (otilo)
ajawo yin (otilo)
iyawo yin (otilo)
l’ati mainland (otilo)
ma bo ni lekki (otilo)
lekki ninu loh loh (otilo)
a ma shey uber fun (otilo)
a ma shey utuba fun (otilo)
tal’efin ta’yin? (otilo)
ab’ori nta yin? (otilo)
iyawo oga yin (otilo)
iyawo egbon yin (otilo)
t’oba ti fi si (otilo)
won ba pada yo+o (otilo)
omo t’en gbe wa (otilo)
awa l’agbe lo oh (otilo)
okada l’efi gbe wa (otilo)
benz l’afi gbe lo oh (otilo)
a ma ra fendi fun (otilo)
a ma ra gucci fun (otilo)
t’oba ti g’eshin kutakuta (otilo)
kole mo’na ile mo (otilo)
ma bo l’odo gattuso (otilo)
elegushi wo’nu oniru (otilo)
t’omo ti mu azul (otilo)
e wa ni “k’oma ba sun” (otilo)
fa+la+ti+do (otilo)
re+mi+re+do (otilo)
so+so+mi+re+do+do (otilo)
fa+so+mi+la+ti+do (otilo)
omo o le buru titi, k’afi f’ekun pa je
e bami gbe oluwa tobi, lekan ti yi pada
ko mu’gbo mo (loud lon fa)
ko fa cigar (shisha lon fa)
ko gba jedi (molly lon gba)
t’oba ti gb’oja, ma na soldier
ko mu’gbo mo oh (loud lon fa)
ko fa cigar (shisha lon fa)
ko gba jedi (molly lon gba)
t’oba ti gb’oja, ma na soldier
(otilo)
oya, soh pe “otilo” (otilo)
izz gone+gone (otilo)
t’apo e bati fuye (otilo)
l’arin awon omo oro (otilo)
awon omo “b’ani, a toro” (otilo)
awon omo “b’ani, a jagba” (otilo)
bawo l’era shey gbe sugar? (otilo)
talo y’owo l’apo picker? (otilo)
oko t’oba pa’na (otilo)
a sanwo “omo taku” (otilo)
t’eba pe ija agbagba (otilo)
ma pe ija omode (otilo)
alagbara lon gb’owo ita (otilo)
oun wa charger (otilo)
ko mo pe won ti yo ‘je (otilo)
t’oba ni “o d’apo e mu” (otilo)
ihahin na lagos (otilo)
t’oba ka e mo woro (otilo)
woro si woro (otilo)
o ma d’eshu (otilo)
t’oba lo ‘je ‘mu jesu (otilo)
oba wa ni sheffield (otilo)
mo mo arowolo (otilo)
mo mo alhaja bolashere (otilo)
l’america (otilo)
lanre typical (otilo)
riliwan kula (otilo)
ato mukaila (otilo)
mo mo bunmi obakoya (otilo)
alagbe mo obelu (otilo)
mo mo dende (otilo)
omo o le buru titi, k’afi f’ekun pa je
e bami gbe oluwa tobi, lekan ti yi pada
ko mu’gbo mo (loud lon fa)
ko fa cigar (shisha lon fa)
ko gba jedi (molly lon gba)
t’oba ti gb’oja, ma na soldier
ko mu’gbo mo oh (loud lon fa)
ko fa cigar (shisha lon fa)
ko gba jedi (molly lon gba)
t’oba ti gb’oja, ma na soldier
(2t on the mix)
Random Lyrics
- ali (kor) - 가시연꽃 (水草) (prickly waterlily) lyrics
- rəsul əfəndiyev - məsti xumar lyrics
- whymedead - ты меня не ищи (do not look for me) lyrics
- reborn tha rebizzle - take heed lyrics
- dave carlos - dahil ikaw lyrics
- hervé (postaal) - autour de moi lyrics
- baby goosey - hellhound lyrics
- bazar et bémols - son temps lyrics
- pablo chill-e - verde y azul lyrics
- voces del rancho - capital del infierno lyrics