azlyrics.biz
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

seun&wumi akinwole - e ho iho ayo lyrics

Loading...

ẹ hó ìhó ayọ̀ sí oluwa, gbogbo ilẹ̀ ayé.
ẹ fi ayọ̀ sin oluwa.
ẹ wá siwaju rẹ̀ pẹlu orin ayọ̀.
ẹ mọ̀ dájú pé oluwa ni ọlọrun,
òun ló dá wa, òun ló ni wá;
àwa ni eniyan rẹ̀,
àwa sì ni agbo aguntan rẹ̀.
ẹ wọ ẹnubodè rẹ̀ tẹ̀yin tọpẹ́,
kí ẹ sì wọ inú àgbàlá rẹ̀ tẹ̀yin tìyìn.
ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ̀,
kí ẹ sì máa yin orúkọ rẹ̀.
nítorí oluwa ṣeun;
ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae,
òtítọ́ rẹ̀ sì wà láti ìran dé ìran.



Random Lyrics

HOT LYRICS

Loading...