sunday ajanaku - arugbo ojo lyrics
arugbo ojo lyrics by sunday ajanaku
(chant)
iba oooooo iba, f’eledumare
akoda aye, aseda orun
olowogbogboro tin yo mo re ninu ofin
olukagun orun, olorun nla
olorun aanu, alewilese, aleselewi
gbongbo idile jesse, ekun oko pharaoh
emini tin je emi ni, emi ni maseberu
adeda, aseda, awoeda, amoeda, eledaa ohun gbogbo
ahhh yagboyaju okunrin ogun, jagunjagun ode orun
olorun kan lailai, oba to mo wa to mó wa, alagbada ina, alawotele orun
(chorus)
eledumare atobajaye ma jaya lolo
arugbo ojo, arugbo ojo
eledumare atobajaye ma jaya lolo
arugbo ojo, arugbo ojo
verse 1:
when i think of the goodness of jesus and all he has done for me
i will bere jo
i will bere jo
he has conquered the death and conquered the world for me in vic-to-ry o
i will bere jo
i will bere jo
mo ma jijo mo ma s’ayo m’ayo mo ma k’aleluya o
i will bere jo
i will bere jo
mo ma jijo mo ma s’ayo m’ayo mo ma k’aleluya o
i will bere jo o o
i will bere jo
(repeat chorus)
(rap)
mo gboju mi soke ibo niran lowo mi tiwa
awon kan lero pe odo babalawo loti wa
baba god is my shield, my joy and my savior
nigba ishoro funmi oruko olorun kin shewo
nigba iponju bade baba god mumi la koja
eyin arogo bogoje iwaju yin ni ma koja
iwaju yin dark baba god bami tan atupa
kima lor shinor debomi baba bami tan atupa
baba jeki ojo ola mi yen bright ju ti halogen
kode feje jesu re cover mi biti canopy
baba let your glory so shine before us now
kawon ota makor success story mi bi chorus now
baba elevate kan ma le ti gate mi
ki ayo ati ibukun dema saturate mi
baba bless mi kan male castigate mi
mo sure pojor ola mi madara iyen ni faith mi
(repeat chorus)
(vamp)
call: arugbo ojo o
resp: arugbo ojo o
call: arugbo ojo o
adagba maatepa
adagba maa lo gl-ss o
the lily is the valley
the bright and morning star
ekwueme
baba o
olowogbogboro
ti n y’omo re lofin aye
baami agbalagba
agbalagba oye
mighty man in battle
ancient of days
bo e kom do
n0body like you
eledumare atobajaye ma jaya lolo
arugbo ojo, arugbo ojo
eledumare atobajaye ma jaya lolo
arugbo ojo, arugbo ojo
Random Lyrics
- for science - nothing constant lyrics
- lauren demaio - locked eyes lyrics
- aanthems - crispr lyrics
- lil rock look - the charlies freestyle lyrics
- costa gold - bailarina lyrics
- soner sarıkabadayı - boza boza lyrics
- dom mclennon - back to home /// stowaway [demo] lyrics
- riding the low - great day out for the boys (demo) lyrics
- zeo jaweed - n'oluyo lyrics
- lee kernaghan - when country comes lyrics