teejay’s wrld - 6ix feet (grave) lyrics
bhad+mharn+tinz!
inna+lillahi+wainallilehi+rajihun
odoeh lati wa, odoeh na lama pada si ìwó ólorun
ekun ton mon sùn ko tó wayè shéybi owun na loyé
tori otimó pé ogun layé lati ódò awon obieh méjéji
ilé áyé ásan wiwá láwá liló ná dé ni àmàló
mo sorry fuén eh, ìwó toh wale áyé móyà toh mòpé oma lonjokan
álapadupe lólórun kosé ni tolé bi léjò
ádura ni komà pé kémieh má tówó eyan bó
ìwó ton dúpé pé ojogún towa nn fí ní áwón éyan lárá
shá ránti ìjo tó bámá wé éh láshó fún fún tómá kírún síèh lárá
cause everything that begins must surely have a end
áwa nájá láyé ni, érépá ni táh bán kí ràwà ní happy new year
nì lókán péhh tóbá súnn tóbá jí ólórún mómó jí èh ní
tóh bá dúnú gbo gbo nnkan toh kosáyé okó fi shádanwo fún eh ni
gbo gbo éré tón sáá pé ofé dá shéy bi átélówó lowá
owún kówún tèdá bán shéy koma wúwà bì ènì tio nìdólá
ìlé áyé ésé méfá áfówó báfí lé
shámá ro kotó shéy torí íjó tóbá má wólé
6ix feet so deep,that’s where to be bury after death
égbé áyé shéréré torí ijó tóbá má kú ìwó átií ìwá èh lèh
ìlé áyé ésé méfá áfówó báfí lé
shámá ro kotó shéy torí íjó tóbá má wólé
6ix feet so deep,that’s where to be bury after death
égbé áyé shéréré torí ijó tóbá má kú ìwó átií ìwá èh lèh
ìnúmí kómá dúní tínbá gbó ìbì tí tópé álábí tín yín ólórún
áye yì olè àwa táá wán béh nà là mú áyé rórún
i make dou frequently when i was nineteen
máfí nnkán gbá kán lówó mí ní keyword ádurá mí lódó sáttí
kóséni tóh lé tú shéy ólórún óbá wóó
èdá gbódó shóró áráéh tórí kósálábáró
shéy réré bálé shéy dádá siéh
èyán òdé shéy nn pónlé ìwá éh ná lómá tún fí bú éhh
kó séwé tó jábó lárá gí tólórún óbá mí ómó sí
áyé gbá jéjé èdá èmá lómá wúwá táló fé múmí sí
tóbá áyé óbàriéh má fí jókán gbá gbé órún
kósé ní tío ní jéré íshéy éh, bó shéy físíbí ná lótún shéy fí sóún
ómó óbá wóó kósí nnkán tió tí shélé rí
ìyin tóbá rí tóh yáéh lénú shé shélé lójú èh ní
rórá sóró fún yán tórí gbó gbó èní tón sóró fún kòló understand
élómí má shí éh gbó èsí tómá fú èh nì pé ná wá óhh!
ìlé áyé ésé méfá áfówó báfí lé
shámá ro kotó shéy torí íjó tóbá má wólé
6ix feet so deep,that’s where to be bury after death
égbé áyé shéréré torí ijó tóbá má kú ìwó átií ìwá èh lèh
ìlé áyé ésé méfá áfówó báfí lé
shámá ro kotó shéy torí íjó tóbá má wólé
6ix feet so deep,that’s wherе to be bury after death
égbé áyé shéréré torí ijó tóbá má kú ìwó átií ìwá èh lèh
Random Lyrics
- бригадный подряд (brigade contract) - жизнь (life) lyrics
- evan slade - la lyrics
- kaue safadinho - nega lyrics
- xxxmanera - domino lyrics
- 北出菜奈 (nana kitade) - 13日の金曜日 (13nichi no kinyo-bi) lyrics
- yoselin - baila conmigo lyrics
- makosir - litt for sent lyrics
- eliott - control lyrics
- rochdi - le noctambule lyrics
- bastille - survivin’ (mtv unplugged) lyrics