azlyrics.biz
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

tope alabi - oluwa otobi lyrics

Loading...

oluwa o tobi, o tobi o, o tobi
ko s’eni t’a le fi s’afiwe re o, o tobi
ko s’eda t’a le fi s’akawe re o, o tobi

oluwa
oluwa o tobi, o tobi o, o tobi
ko s’eni t’a le fi s’afiwe re o, o tobi
ko s’eda t’a le fi s’akawe re o, o tobi
oluwa
o tobi o, oluwa giga lorile ede gbogbo
gbigbega ni o, iwo lo logo ni orun
pupopupo ni o, o koja omi okun at’osa, o ga po
ajulo o o se julo

oluwa o tobi, o tobi o, o tobi
ko s’eni t’a le fi s’afiwe re o, o tobi
ko s’eda t’a le fi s’akawe re o, o tobi
oluwa
oba lori aye, o tobi o eh
agba’ni loko eru, olominira to n de’ni lorun
o fi titobi gba mi lowo ogun t’apa obi mi o ka
olugbeja mi to ba mi r’ogun lai mu mi lo t’o segun
akoni ni o o
oluwa o tobi, o tobi o, o tobi
ko s’eni t’a le fi s’afiwe re o, o tobi
ko s’eda t’a le fi s’akawe re o, o tobi
oluwa
b’o ti tobi to oo, laanu re tobi
b’o ti tobi se o, ododo re tobi o
o tobi tife tife, oni majemu ti kii ye
aro nla to gbo jije mimu aye gbogbo alai le tan
ogbon to koja ori aye gbogbo ooo
oluwa o tobi, o tobi o, o tobi
ko s’eni t’a le fi s’afiwe re o, o tobi
ko s’eda t’a le fi s’akawe re o, o tobi
oluwa
akoko o tobi, o tobi o
oluwa
ipilese ogborin o yeye
o tobi
ibere eni to f’ogbon da ohun gbogbo
oluwa
igbeyin ola nla, o la la oo
o tobi
opin aye a’torun ko si ‘ru re
oluwa
o tobi, o o se s’akawe lailai o
o tobi
agbaagba merinlelogun nki o, o tobi
oluwa
awon angeli won n ki o, o tobi
o tobi
olorun elijah ireti ajanaku
oluwa
o ma tobi laye mi, o tobi ooo
o tobi
iwo lo gb’orin t’o o ga, t’o gun, t’o tun fe
oluwa
o ga, o gun, o fe, o jin, o tobi la la
o tobi



Random Lyrics

HOT LYRICS

Loading...