xhaka-zulu - ayé lyrics
hook
ibí gbo gbo e re oké lọ rè bà
ibí gbo gbo e rè oké lọ rè bà
ibí gbo gbo e rè oké lọ rè bà
ibí gbo gbo e rè oké lọ rè bá
bridge
bó ṣe ayé rè o ma kù
bó ṣe ayé rè o ma kú
kilo tun wá ku abeg you make you do good oh
ire l’ope ika òpe ọlọrun o bímọ ẹsan lóbí
ayé l’ọja òrun ní ilé, ma gbádùn ọjà gbà gbé ilé
chorus
ayé! ayé!! ayé!!! ayé!!!!
asán ma l’ayé
ayé! ayé!!
aye toto, aye akamara
ọpọ nínú ayé, nínú ayé tiwọn tí jẹ ma ayé
ẹdà mi ma sùn ma mọ jẹ kiwọn jẹ mi mọ ayé
ayé! ayé!! ayé!!! ayé!!!!
ayé kan lo wa
ayé! ayé!! ayé!!!
ka sha ma jẹ àiyé
ayé! ayé!! ayé!!! ayé!!!!
ọrẹ nínú ayé
ajé! ajé!! ajé!!! ajé!!!
la fí gbádùn ayé
verse
ọrẹ mí àní ma ṣe ahun , ọmọ a jẹ ìgbín jẹ ikarahun
to ba ni l’ọwọ koni ṣe ahun, a fi àìní lọwọ l’ofe jọ ahun
ibadan ti o mọ ko jọ layipo, ij+pa ti o mọ o jọ yanibo
àtòrì mó l’ayé bi a fi sí waju a fi sí ẹyin
i don’t know how you play
but i’m ready to play how you wan play
i let them know the xharks don’t play
i’ve really got to show the xharks don’t play
see, this life if you do good you go see good so do good
see this life if you do good you go see good so do good
korin
chorus
ayé! ayé!! ayé!!! ayé!!!!
asán ma l’ayé
ayé! ayé!!
aye toto, aye akamara
ọpọ nínú ayé, nínú ayé tiwọn tí jẹ ma ayé
ẹdà mi ma sùn ma mọ jẹ kiwọn jẹ mi mọ ayé
ayé! ayé!! ayé!!! ayé!!!!
ayé kan lo wa
ayé! ayé!! ayé!!! ayé!!!!
ka sha ma jẹ àiyé
ayé! ayé!! ayé!!! ayé!!!!
ọrẹ nínú ayé
ajé! ajé!! ajé!!! ajé!!!
la fí gbádùn ayé
hook
ibí gbo gbo e re oké lọ rè ba
ibí gbo gbo e re oké lọ rè ba
ibí gbo gbo e re oké lọ rè ba
ibí gbo gbo e re oké lọ rè ba
chorus
ayé! ayé!! ayé!!! ayé!!!!
asán ma l’ayé
ayé! ayé!!
aye toto, aye akamara
ọpọ nínú ayé, nínú ayé tiwọn tí jẹ ma ayé
ẹdà mi ma sùn ma mọ jẹ kiwọn jẹ mi mọ ayé
ayé! ayé!! ayé!!! ayé!!!!
ayé kan lo wa
ayé! ayé!! ayé!!! ayé!!!
ka sha ma jẹ àiyé
ayé! ayé!! ayé!!! ayé!!!!
ọrẹ nínú ayé
ajé! ajé!! ajé!!! ajé!!!
la fí gbádùn ayé
Random Lyrics
- artla & nashir - date you lyrics
- patient sixty-seven - stay paranoid ii lyrics
- ledencoff - 1337 lyrics
- yadday li - харибо lyrics
- swerzie - sight switching lyrics
- steve void & strange fruits - numb lyrics
- yng dafi & januarj - future lyrics
- nonamera - dye in lily lyrics
- yts nasa - all alone lyrics
- the fullerenes - big mistake lyrics