yung jxu - aiyé (feat. guccimane-wa, lyrical, omobolaji & steenoboi) lyrics
yeah asorogbayi lomo náà
incase you don’t know
know now hmmmmmmmmn
yeah yeah ohhhhhhh
alaye oh ah
aiyé aiyé aiyé aiyé oh
mọ r’ayé mọ sá f’ayé
aiyé aiyé aiyé aiyé oh
aiyé tótó
aiyé aiyé àiyé aiyé oh
mọ r’ayé mọ sá f’ayé
aiyé aiyé aiyé aiyé oh
aiyé tótó
i love my life
hin pay me now
i no wan dey run
inside this life oh
but still on still
man go make am
i remember then
inside the hood
challenges could be challenging
talo ní mọto tí kò ní engine
i love my life
hin pay me now
i no wan dey run
inside this life oh
but still on still
man go make am
i remember then
inside the hood
k’ayé máṣe bámi wí
k’ayé máṣe bámi já
kín máṣe b’aye lẹjọ
torí ayé akamara
aiyé aiyé aiyé aiyé oh
mọ r’ayé mọ sá f’ayé
aiyé aiyé aiyé aiyé oh
aiyé tótó
aiyé aiyé àiyé aiyé oh
mọ r’ayé mọ sá f’ayé
aiyé aiyé aiyé aiyé oh
aiyé tótó
aiyé burú gán w’aya é nphoto
aiyé akamara
girlfriend gán w’abo nnika oh
aiyé burú gán bere lowo jega
reason t’afi nteka
naija láti nri ẹka
wọn tún pariwo up nepa l’otun l’osi
t’oba nwa wonder o ma ni cholera
wọn wà nwa wà ní solomade
àwọn wò nìyẹn àwa dé ti dé
bàbá ayomide l’otun nwa npemi
àwọn gán ọ dé lè tún wá lémi
aiyé aiyé aiyé akamara
aiyé tó má y’omo tún lai lo camera
aiyé burú gán aiyé tún n’ika
t’oba ti bẹ sí wón
wọn má rí e ni soka
toochi lyrical noni eshamo
i love my life
hin pay me now
i no wan dey run
inside this life oh
but still on still
man go make am
i remember then
inside the hood
aiyé ló ṣọmọ d’ẹru
wọn tún s’ẹru d’ọba
wọn ní mọ bólájí
wọn tún ní kín tún lowa
away my pain my gain
oribu’ away
make dem call my name
kin ri témi se
kín lowo laye
make dem call my name
away away
oribu’ away
aiyé aiyé aiyé aiyé oh
mọ r’ayé mọ sá f’ayé
aiyé aiyé aiyé aiyé oh
aiyé tótó
aiyé aiyé àiyé aiyé oh
mọ r’ayé mọ sá f’ayé
aiyé aiyé aiyé aiyé oh
aiyé tótó
Random Lyrics
- kwe the artist - vibe on stûck lyrics
- isabel silva - desperta lyrics
- bobby goldsboro - childhood 1949 lyrics
- gkko - diferente lyrics
- guided by voices - roll me to heaven lyrics
- plan&tbubu - my way lyrics
- kazz the virgo - girl lyrics
- naïl 5phal - allume lyrics
- anderson, of a painter - like flies lyrics
- rauw alejandro - de cora ﹤3* lyrics