zlatan - omo ologo lyrics
[verse 1]
till the second coming of jesus christ, i go dey give them
mo t’ajero from monday till friday, jaiye ni weekend
i don’t need up to sixteen bars to prove that i am wicked
and i bet you all can testify that this young n+gga is gifted
oya wọn lẹnu bi mo shey tana tan seventeen eighteen nineteen
best act afrimma, la ba gboriwo quarantine
lockdown fẹ run wa down, la ba fariga fara ki
ki lọn ma gain ti n ba fall
tẹ ba r’ota mi, ẹ bami bi
[bridge]
kuonbe!
lamba yapa oloungbo walahitalahi (walahitalahi)
god dey bless me too much me i no deny (no dey)
and that’s why they all chasing when i’m driving by (skrr, skrr)
i pray make my samson no ever meet delilah
[verse 2]
see
symbol of hope
for their eye e be like soap
wọn fẹ ki n ma fayawọ bi crocodile aṣọ lacostе
o wa lara mi, o kun se, o tun sẹ danu
fun eyin tẹ komije, tẹ n gbọn mi mu, ẹ o ni ridamu
[pre+chorus]
kuonbе!
ọmọ trenches ninu lamborghini
vvs lọrun. jaiye n santorini
aṣọ gucci, sokoto amiri
toba shele wa mo pe ẹsha ni richard mille
[chorus]
ọmọ ologo!
to ba ti rimi, o rọmọ ologo
ọmọ ologo!
to ba ti rimi, o rọmọ ologo
ọmọ ologo!
to ba ti rimi, o rọmọ ologo
ọmọ ologo!
to ba ti rimi, o rọmọ ologo
[verse 3]
kuonbe sẹ
stack the money up, stack the money up owo lo shey igboro (kilowi?)
rale fun mummy, ra fun daddy, maje k’owo s’ojoro (kilosọ?)
tẹ pa mo sẹ, ni maga
o di dandan ẹsẹ a gun (jenmọ)
oma sisẹ, oma laagun (jenmọ)
o de le sọ aagun di’gbadun
e no matter how the background dey be
o le di arabanbi, o le sọ bye+bye si garri
all man for himself, oju lari
bọrọ yi shey n bayin, bẹẹ na lo n bamiwi (kiloso?)
[pre+chorus]
ọmọ trenches ninu lamborghini (lambo)
vvs lọrun, jaiye santorini
asọ gucci, sokoto amiri
toba shele wa mo pe esha ni richard mille (esha)
[chorus]
ọmọ ologo!
to ba ti rimi, o rọmọ ologo
ọmọ ologo!
to ba ti rimi, o rọmọ ologo
ọmọ ologo!
to ba ti rimi, o rọmọ ologo
ọmọ ologo!
to ba ti rimi, o rọmọ ologo
[outro]
kuonbe sẹ
stack the money up, stack the money up owo lo shey igboro (kilowi?)
rale fun mummy, ra fun daddy, majẹ k’owo s’ojoro (kilosọ?)
tẹ pa mo sẹ, ni maga
o di dandan ẹsẹ a gun
oma sisẹ, oma laagun
o de le sọ aagun di’gbadun
Random Lyrics
- 13slavs - too good lyrics
- various artists - sweetest thing lyrics
- clique (rapper) - hear me now lyrics
- lnf jc - see my pain lyrics
- bné (fra) - freestyle zone 4 lyrics
- seventhirtyatmorning - #geeksquad lyrics
- leonis - parle moi lyrics
- edu espinal - recitaré lyrics
- televisor - find that someone (tobtok remix) lyrics
- j9ueve - sans faire exprès lyrics