chidinma - ko s'oba bire lyrics
[chorus]
laye lorun kosoba biire
(laye lorun kosoba biire)
eleru niyin, alagbawi eda’o
(laye lorun kosoba biire)
aduro tini, lojo iponju mi o
(laye lorun kosoba biire)
oran ni nise, atu sini lo o
(laye lorun kosoba biire)
[verse 1]
gbigbe ga, loruko re
tito bi, loruko baba
talaba fi owe, ekun oko pharaoh
hossana iwo lo peye
oforun nikan, se kiki da wura
ogba mi lowo ota aye mi o
ose o, kosoba biire
[chorus]
laye lorun kosoba biire
(laye lorun kosoba biire)
eleru niyin, alagbawi eda’o
(laye lorun kosoba biire)
aduro tini, lojo iponju mi o
(laye lorun kosoba biire)
oran ni nise, atu sini lo o
(laye lorun kosoba biire)
[verse 2]
olugbega mi, atoba tele
oluwasanmi, awe maye hun
onibu ola, ola yan turu
atobiloba, adi ma se tu
mojuba fun alada wura
mo kira fun oba aye mi o
ose o, kosoba biire
talaba fi owе, ekun oko pharaoh
hossana iwo lo peye
oforun nikan, se kiki da wura
ogba mi lowo ota ayе mi o
ose o, kosoba biire
[chorus]
laye lorun kosoba biire
(laye lorun kosoba biire)
eleru niyin, alagbawi eda’o
(laye lorun kosoba biire)
aduro tini, lojo iponju mi o
(laye lorun kosoba biire)
oran ni nise, atu sini lo o, ose
(laye lorun kosoba biire)
Random Lyrics
- war - youngblood (livin' in the streets) lyrics
- duch - zvyknúť si lyrics
- crm (au) - hear me out lyrics
- anzo - umfowethu lyrics
- mesori grey - urgent lyrics
- czah the dream - high on life lyrics
- theo rose - gipsy run lyrics
- kidup - vento lyrics
- prod. bad dude - crypt - bad friend (remix 2) (5 minutes remix) lyrics
- satyr (atlanta) - seam lyrics