azlyrics.biz
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

debra crown-olu – korin si oluwa lyrics

Loading...

emi o kọrin si oluwa, nitoriti
o pọ′ li ogo:
ẹṣin ati ẹlẹṣin on li o bì ṣubu

sinu okun pupa.
oluwa li agbara ati orin mi,
on li o si di ìgbala mi:
eyi li ọlọrun mi, emi o si fi ìyin fun u;
kabioyesi mo se iba re
emi o kọrin si oluwa,
emi o kọrin si oluwa, nitoriti
o pọ’ li ogo:
ẹṣin ati ẹlẹṣin on li o bì ṣubu
sinu okun pupa.
oluwa, li asà fun mi; ogo mi;
olugbe ori mi soke.
emi fi ohùn mi kigbe si oluwa,
o si gbohùn mi lati òke mimọ′ rẹ’ wá.
emi o kọrin si oluwa,
oba to ‘n be ninu orun
gbega mi o le sai gbega titi lai.
o ran omo ni se fayati
gbega mi o le sai gbega titi lai.
you are bigger than the biggest
olowogbogboro ti ′n gba omo re lofin
a se kabiesi re eladumare tewogbope
(omo egbala gbo in so ke).
oba to ti wa o, k′ aye to wa
ti si tun ma wa nigba ti aye ko no si mo
mo ni, oluwa n’ be bi ti ati jo
a wa la o sin baba bi ta ti jo.
bri:
ologun li oluwa; oluwa li orukọ rẹ′.
ọwọ’ ọtún rẹ li ogo ninu agbara:
ọwọ′ ọtún rẹ fọ’ ọtá tútu.
emi o kọrin si oluwa,
mo korin hallelujah
mo ke hallelujah
ona to di ti la o
oluwa la ona ni bi to ko so na
ona to di ti la o
ogo oluwa won la ye mi



Random Lyrics

HOT LYRICS

Loading...